Aarẹ Muhammadu Buhari ti ṣekilọ pe ki awọn eeyan ma waa ki oun nile lọjọ ọdun…
Category: Ìròyìn
Wọn dana sun awọn adigunjale ti wọn fọ banki l’Okeho, ti wọn tun pa ọlọpaa kan
Nnkan ko ṣenuure fun aọn adigunjale kan ti awọn araalu dana sun ni Ọjọruu, Wẹsidee, ọsẹ…
Ijọba yoo ṣi awọn ileejọsin loṣu to n bọ nipinlẹ Ogun– Dapọ Abiọdun
Adefunkẹ Adebiyi, Ogun Ọjọruu, Wẹsidee, ọsẹ yii, ni Gomina ipinlẹ Ogun, Omọọba Dapọ Abiọdun, kede lọfiisi…
Godwin fipa ba abirun lo pọ ni Sango, lo ba loun ti ṣe e tan koun too mọ pe ko daa
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọmọbinrin kan ti ara rẹ ko da pe pade agbako ibasun lanaa ode…
O ma ṣe o, awọn janduku pa eeyan mẹtala ninu mọlẹbi kan naa ni Kogi
Eeyan mẹrinla lawọn janduku kan pa loru Ọjọruu, Wẹsidee, ọsẹ yii, nipinlẹ Kogi, nigba ti awọn…
Eyi le o, lọjọ kan ṣoṣo, Korona paayan mẹta l’Ọyọọ
Ọlawale Ajao, Ibadan Gende Ọlọrun mẹta lajakalẹ arun Korona pa lọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọsẹ yii. O…
Ayedatiwa ni yoo ṣe igbakeji Gomina Akeredolu ninu eto idibo ti yoo waye loṣu kẹwaa
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Gomina ipinlẹ Ondo, Rotimi Akeredolu ti forukọ ẹni to fẹẹ fi ṣe igbakeji…
Oku rẹpẹtẹ ni Kaduna: Awọn Fulani onimaalu fẹẹ dogun silẹ ni o
Ihooho ni pupọ ninu wọn jade, paapaa awọn ti wọn jẹ agbalagba ninu wọn. Awọn obinrin…
Haa, obinrin yii si n gba iṣo mọ ọmọ ọkọ ẹ kekere yii lori
Awọn ọlọpaa Ṣagamu ti mu un o. Abimbọla. Koda wọn tun mu ọkọ ẹ naa, Taiwo…
Pasito Kumuyi, olori ijọ Deeper Life, kọ Bibeli tuntun
Olori ati Oludasilẹ ijọ awọn Dipa (Deeper Life) Pasitọ William Kumuyi, ti kọ Bibeli tuntun ni…
Awọn eleyii fipa ba obinrin sun l’Ogijo, wọn tun fidio rẹ
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ṣọla Ọlaoluwa, Ibrahim Kẹhinde ati Lukman Banjoko lẹ n wo yii, awọn pẹlu…