Ó Ṣojú Mi Kòró

O ṣoju mi koro (Apa Kin-in-ni)

Naijiria ki i ṣe ti Fulani, wọn n tan ara wọn jẹ lasan ni NIgbakigba ti wọn ba n kọ itan orile-ede yii lakọtun, itan Naijiria ko le sọ daadaa nipa Aarẹ Muhammadu Buhari. Ohun ti eleyii ko ṣe ni i ri bẹẹ ni pe oun naa ko ṣe daadaa fun Naijiria, …

Read More »

O ṣoju mi koro (Apa Keji)

Kin ni Pasitọ Tunde Bakare n fẹ gan-an? Kin ni Pasitọ Tunde Bakare n fẹ gan-an? Ki lo n wa kiri? KI lo fẹẹ gba? Nibo lo ti fẹẹ gba a? Ki lo si fẹẹ fi gba a? Loootọ ni ọkunrin ajihinrere yii ti kede lọjọ kejilelogun, oṣu kẹsan-an, 2019, …

Read More »

O ṣoju mi koro (Apa Kin-in-ni)

Bi eti Buhari ko ba di, o yẹ ko gbọ ohun ti Kukah n sọ Bo ba ṣe pe Aarẹ Muhammadu Buhari ṣi n gbọrọ, ti laakaye rẹ si n gbe ọrọ ti awọn eeyan ba sọ, o yẹ ko feti si ọrọ ti Olori ijọ Aguda agbegbe Ṣokoto, Biṣọọbu …

Read More »

O ṣoju mi koro (Apa Keji)

Ẹ jẹ ka ṣọra fun Koro o Arun Korona ti wọn pariwo ẹ nibẹrẹ ọdun yii ti tun bẹrẹ lakọtun o. Kaakiri ipinlẹ ni ijọba ti n ṣe ofin oriṣiiriṣii, ohun ti wọn si n ṣe ni bi arun naa ko ṣe ni i maa gbilẹ si i. Ṣugbọn ọpọlọpọ eeyan ni …

Read More »

O ṣoju mi koro (Apa Kin-in-ni)

Ta lo ji awọn ọmọleewe Kakara gbe gan-an! Nigba ti ariwo sọ pe wọn ji awọn ọmọleewe ojilelọọọdunrun ati mẹta lọ ni Kankara, nipinlẹ Katsina, lọsẹ to lọ lọhun-un, awọn Boko Haram ni wọn kọkọ sare jade, wọn ni awọn lawọn ji awọn ọmọ naa gbe, ati pe idi ti …

Read More »

O ṣoju mi koro (Apa Keji)

Nibo ni Buhari fẹẹ sa gba! Ọrọ Aarẹ Muhammadu Buhari ati awọn eeyan ti wọn wa lẹgbẹẹ rẹ ti wọn n ba a ṣiṣẹ, ọrọ awodi oke ti i ṣe bi ara ilẹ ko ri oun ni. Nigba ti ẹyẹ awodi ba fo soke lala, yoo ro pe awọn eeyan …

Read More »

O ṣoju mi koro (Apa Kin-in-ni)

Pasitọ Adeboye pẹlu owo dọla Ni ti ohun to n ṣẹlẹ ni orilẹ-ede Naijiria wa bayii, ko si aṣaaju rere kan ti yoo ni ọrọ naa ko kan oun, afi awọn aṣaaju buruku nikan. Nnkan kan n fojoojumọ bajẹ ṣaa ni, ohun gbogbo to dara daadaa tẹlẹ si bajẹ loju …

Read More »

O ṣoju mi koro (Apa Keji)

Kin ni Tọpẹ Alabi n fẹdi ara rẹ sita bayii fun Olorin ẹmi gidi ni Arabinrin Tọpẹ Alabi, ọpọlọpọ awọn Krisitẹni ati awọn ti ki i tilẹ ẹ ṣe Krisitiẹni rara, ni wọn fẹran orin rẹ, wọn aa si maa kan saara si i bo ba n kọrin ẹmi fun …

Read More »
//unbeedrillom.com/4/4998019