Patako ipolongo Ọṣinbajo fun ipo aarẹ lu ipinlẹ Kwara pa

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Bo tilẹ jẹ pe ko ti i jade lati fi erongba rẹ lati…

Adajọ ti ju Sifu-difẹnsi to fipa ba ọmọ ọdun mẹtala lo pọ l’Ekiti sẹwọn

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ile-ẹjọ Majisreeti kan to wa l’Ado-Ekiti, ti paṣẹ pe ki ọkunrin ẹni ọdun…

Awọn agbebọ tun pa eeyan mọkanla ni abule kan nipinlẹ Plateau

Jọkẹ Amọri Ko din ni eeyan mọkanla ti wọn tun pade iku ojiji nibi akọlu awọn…

Apapọ ẹgbẹ ọdọ ati akẹkọọ bii mẹtadinlọgọta fọwọ si Ọṣinbajo lati dupo aarẹ Naijiria

Jọkẹ Amọri Ẹgbẹ kan to jẹ apapọ awọn akẹkọọ ati ọdọ ti wọn pe ni ‘National…

O ma ṣe o gomina ipinlẹ Ọyọ telẹ, Alao Akala ti ku o

Jọkẹ Amọri A-gbọ-sọgba-nu ni iroyin iku gomina to ti jẹ nipinlẹ Ọyọ, Adebayọ Alao Akala jẹ…

Igbimọ to n pẹtu saawọ ninu ẹgbẹ APC ti gunlẹ si Kwara

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Aje, Monde, ọṣẹ yii ni ẹgbẹ oṣelu APC nipinlẹ Kwara gbalejo igbimọ ti…

Gomina ipinlẹ Ebonyi, David Umahi, ṣabẹwo si Buhari, o loun naa fẹẹ dupo aarẹ

Faith Adebọla Ko ti i pe wakati mẹrinlelogun ti Aṣiwaju Bọla Ahmed Tinubu ṣabẹwo si Aarẹ…

Afẹnifẹre ko ni i ṣatilẹyin fẹnikẹni, afi ti wọn ba kọkọ tun iwe ofin Naijiria ṣe

Faith Adebọla, Eko  Ẹgbẹ Afẹnifẹre, ẹgbẹ to n jijangbara fun ilẹ Yoruba ti sọ pe awọn…

Dukia rẹpẹtẹ ṣofo sinu ijanba ina lọja Agbeni, n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Dukia ti ko mọ ni owo kekere lo ṣegbe sinu ijamba ina to…

Ala lasan ni Tinubu to loun fẹẹ ṣe aarẹ Naijiria n la-Bọde George

Faith Adebọla, Eko Igbakeji alaga ẹgbẹ oṣelu PDP nigba kan, Oloye Bọde George, ti sọrọ nipa…

Olori ijọba fidi-hẹ nigba kan, Ernest Shonekan, ti ku o

Jọkẹ Amọri Olori  ijọba fidi-hẹ lorileede wa nigba kan, Ernest Shonẹkan ti jade laye lẹni ọdun…