Awọn to n bẹ ọpa epo yọnda odidi tanka fawọn Sifu Difẹnsi Ogun, wọn sa lọ patapata

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Lọjọ Ẹti, Furaidee, ọjọ kẹtalelogun, oṣu kẹrin yii, ileeṣẹ Sifu Difẹnsi ipinlẹ Ogun…

Ara kenge: APC ṣedanwo fawọn ondije sipo alaga kansu wọn ni Kaduna

Faith Adebọla Afi bii ẹni fẹẹ ṣedanwo Wayẹẹki tabi Jambu, lawọn ti wọn wọn fẹẹ dije…

Ẹ waa wo tiṣa to n fipa ba awọn akẹkọọ ọkunrin to n kọ nileewe lo pọ n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Ọwọ ọlọpaa ti tẹ olukọ ileewe aladaani kan n’Ibadan, Ọlawuyi Ebenezer, ẹni to…

Ko le si eto idibo lọdun 2023, afi ti wọn ba ṣatunṣe si iwe ofin ilẹ wa- Ẹgbẹ Afẹnifẹre

Faith Adebọla, Eko Ẹgbẹ ajijagbara ilẹ Yoruba nni, Afẹnifẹre, ti sọ gbangba gbangba pe bii igba…

Ibi ti Fatai ti n mu Kọlapọ wọ ẹgbẹ okunkun lawọn ọlọpaa ka wọn mọ n’Ikorodu

Faith Adebọla, Eko Fatai Kalejaiye, ẹni ọdun mẹẹẹdọgbọn, ti wọn lo n gbe Ojule kọkandinlogun, adugbo…

Awọn ajinigbe ji Alaga gbe lọna oko rẹ l’Oke-Onigbin, ni Kwara

Stephen Ajagbe, Ilorin Oniṣowo pataki kan, Alhaji Alaga Ọlayẹmi, lawọn ajinigbe bii meje ji gbe l’Ọjọbọ,…

Ọwọ ti tẹ Akpan atọrẹ ẹ ti wọn gbimọ-pọ dumbu ọga wọn bii ẹran l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọwọ ọlọpaa ipinlẹ Ondo ti pada tẹ Emmanuel Akpan, ọmọ ọdọ to dumbu…

Ijọba Eko so gbigba abẹrẹ ajẹsara Korona rọ na

Faith Adebọla, Eko Ijọba ipinlẹ Eko ti paṣẹ pe ki wọn tilẹkun gbogbo ibudo ti wọn…

Ẹni kan ku ninu ijamba ọkọ to ṣẹlẹ loju ọna Gbọngan s’Ibadan

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọkunrin kan ti padanu ẹmi rẹ ninu ijamba ọkọ to ṣẹlẹ l’Ọjọbọ, Tọsidee,…

Eyi ni bi wọn ṣe tẹ Yinka Odumakin nitẹẹ ẹyẹ l’Ekoo, awọn eeyan sọrọ iwuri nipa rẹ

Adefunkẹ Adebiyi Ka ku lọmọde ko yẹ ni, o san ju keeyan dagba ko ma ni…

Dapọ Abiọdun fun akẹkọọ Ogun to yege ju lọ ni LASU ni miliọnu meji naira ati ile kan

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Idunnu ṣubu lu ayọ fawọn akẹkọọ meji kan, Ọladimeji Ṣotunde, ọmọ bibi ipinlẹ Ogun…