Nitori ajẹsilẹ owo-oṣu, awọn oṣiṣẹ fẹẹ gbena woju Akeredolu l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ  Awọn aṣaaju ẹgbẹ oṣiṣẹ ipinlẹ Ondo ti fẹhonu wọn han si gomina ipinlẹ…

Olu Imaṣayi, Ọba Gbadebọ Oni, ti waja

Olu Imaṣayi, Ọba Gbadebọ Oluṣọla Oni, ti waja. Akọwe iroyin fun Gomina Dapọ Abiọdun, Ọgbẹni Kunle…

Ibo abẹle APC l’Ondo: Eyi ni orukọ awọn ti yoo kopa

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Mọkanla ninu awọn oludije sipo gomina ninu ẹgbẹ oṣelu APC ipinlẹ Ondo ni…

Lori iyọnipo igbakeji gomina, adajọ-agba Ondo ja ireti awọn aṣofin kulẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Adajọ-agba ipinlẹ Ondo, Abilekọ Oluwatoyin Akeredolu, ti ja ireti awọn ọmọ ile igbimọ…

O ṣẹlẹ: Alaga APC kọwe fipo silẹ l’Ondo, lo ba darapọ mọ PDP

Alaga ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress nijọba ibilẹ Ẹsẹ Odo, nipinlẹ Ondo, Samuel Ọlọrunwa, ti kọwe…

Iku tun pa aṣofin mi-in l’Ekoo o, Ọnarebu Tunde Buraimọh ti dagbere faye

Faith Adebọla, Eko A-gbọ-sọgba-nu iṣẹlẹ buruku kan niroyin ọhun, afẹmọjumọ owurọ ọjọ Ẹti, Furaidee, oni ni…

Safu halẹ mọ Alaaji, ni dadi wa ba n sare kiri

Baba ti jẹ ẹ tan! Wọn ti gẹẹti baba yin patapata. Alaaji ni, wọn ni kinni…

Ohun to fa wahala lasiko ibo ti wọn di ni 1964 niyi o

Bi ibo ti wọn fẹẹ di ni 1964 yii ti n sun mọle, bẹẹ ni wahala…

Korona pa alaga ẹgbẹ awọn dokita tẹlẹ l’Ondo

Alaga ẹgbẹ awọn dokita nipinlẹ Ondo tẹlẹ, Dokita Michael Adeyẹri, ti dagbere faye lẹyin to lugbadi…

Ija Makinde atiyawo Ajimọbi: Ajimọbi parọ buruku mọ Ariṣekọla ni o

*Aarẹ ko fun un nilẹ kankan *Ladọja paapaa kọ lo nilẹ *Ilẹ ijọba ipinlẹ Ọyọ ni…

Korona: Ọjọgbọn Ibrahim ṣatilẹyin fun ẹkọ ayelujara

Stephen Ajagbe, Ilọrin Ọgba-agba Fasiti Al-Hikmah niluu Ilọrin tẹlẹ, Ọjọgbọn Mohammed Taofeek Ibrahim, ti rọ ijọba…