Nibo lẹyin n gbe, nibo lẹyin wa: Nigba t’Abiọla atawọn eeyan rẹ kọju ija si Awolọwọ ni 1979

*Idi abajọ ree o Ninu oṣu kẹta, lọdun 1979, ipolongo ibo n gbona lalaala laarin awọn…

Ẹja panla miliọnu mẹta aabọ naira ti Ode atọrẹ ẹ ji sọ wọn dero kootu

Faith Adebọla, Eko Arokan ni wọn lo n mu ẹkun asun-un-da wa, arokan ọhun lo ṣẹlẹ…

Baba fi ibalopọ fa idi ọmọ bibi inu ẹ ya l’Akinyẹle, n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Awọn iṣẹlẹ gbankọgbi to n waye lojoojumọ nijọba ibilẹ Akinyẹle, nigboro Ibadan, la…

Ile-ẹjọ sọ awọn mẹrin to paayan sẹwọn l’Ogbomọṣọ, iya meji lo bi awọn mẹrẹẹrin

Ọlawale Ajao, Ibadan Fun bi wọn ṣe pa ọkunrin kan lai ṣẹ, lai ro, awọn ọmọ…

Ọba di meji n’Ikire: Ile-ẹjọ yọ Ọba Falabi nipo

*N lawọn idile to kan ba jawe oye le Ọlanrewaju lori *Idi ti a ko fi…

O ṣoju mi koro

Ki lawọn naa fi yatọ si Hushpuppi, onijibiti agbaye Bi eeyan ba wo awọn ti wọn…

Ọbinrin ti Robbinson fipa ba lo pọ loṣu kẹrin ko ti i gbadun

*Wọn ni eegun ẹyin rẹ ti kan Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Igbobi, l’Ekoo, ni wọn ni ọmọ…

Eyi ni bawọn aṣaaju Hausa-Fulani ṣe ba Naijiria yii jẹ (8)

N ko koriira awọn Hausa-Fulani, nitori ko sohun ti mo fẹẹ fi ikoriira wọn ṣe. Ṣugbọn…

Arun Koronafairọọsi tun ti pa eeyan mẹfa mi-in ni Kwara

Stephen Ajagbe, Ilorin Lẹyin iku olori oṣiṣẹ gomina, Aminu Logun, eeyan mẹfa mi-in ni arun Korona…

Ko si idanwo WAEC lọdun yii – Ijọba apapọ

Oluyinka Ṣoyẹmi Ijọba apapọ ti kede pe ko si idanwo aṣekagba ileewe girama tawọn eeyan mọ…

Igbanisiṣẹ fun ikọ Amọtẹkun bẹrẹ l’Ekiti

Oluyinka Ṣoyẹmi, Ado-Ekiti Ikọ Ekiti State Security Network ti gbogbo eeyan mọ si Amọtẹkun ti bẹrẹ…