Ile-ẹjọ sọ awọn mẹrin to paayan sẹwọn l’Ogbomọṣọ, iya meji lo bi awọn mẹrẹẹrin

Ọlawale Ajao, Ibadan Fun bi wọn ṣe pa ọkunrin kan lai ṣẹ, lai ro, awọn ọmọ…

Ọba di meji n’Ikire: Ile-ẹjọ yọ Ọba Falabi nipo

*N lawọn idile to kan ba jawe oye le Ọlanrewaju lori *Idi ti a ko fi…

O ṣoju mi koro

Ki lawọn naa fi yatọ si Hushpuppi, onijibiti agbaye Bi eeyan ba wo awọn ti wọn…

Ọbinrin ti Robbinson fipa ba lo pọ loṣu kẹrin ko ti i gbadun

*Wọn ni eegun ẹyin rẹ ti kan Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Igbobi, l’Ekoo, ni wọn ni ọmọ…

Eyi ni bawọn aṣaaju Hausa-Fulani ṣe ba Naijiria yii jẹ (8)

N ko koriira awọn Hausa-Fulani, nitori ko sohun ti mo fẹẹ fi ikoriira wọn ṣe. Ṣugbọn…

Arun Koronafairọọsi tun ti pa eeyan mẹfa mi-in ni Kwara

Stephen Ajagbe, Ilorin Lẹyin iku olori oṣiṣẹ gomina, Aminu Logun, eeyan mẹfa mi-in ni arun Korona…

Ko si idanwo WAEC lọdun yii – Ijọba apapọ

Oluyinka Ṣoyẹmi Ijọba apapọ ti kede pe ko si idanwo aṣekagba ileewe girama tawọn eeyan mọ…

Igbanisiṣẹ fun ikọ Amọtẹkun bẹrẹ l’Ekiti

Oluyinka Ṣoyẹmi, Ado-Ekiti Ikọ Ekiti State Security Network ti gbogbo eeyan mọ si Amọtẹkun ti bẹrẹ…

Olori oṣiṣẹ gomina Kwara wọ kaa ilẹ

Stephen Ajagbe, Ilọrin Oku olori oṣiṣẹ gomina Kwara, Oloogbe Aminu Adisa Logun, ti wọ kaa ilẹ…

Kwara: Wọn ti ọsibitu ile ijọba pa nitori iku Aminu Logun

Stephen Ajagbe, Ilọrin Nitori ẹru pe o ṣee ṣe ki olori oṣiṣẹ lọfiisi gomina, Oloogbe Aminu…

Ọran ma waa de bayii o! Pasitọ fun ọmọ ẹ loyun lẹẹmẹta l’Owode-Ẹgbado, o tun ṣẹ ẹ

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Pasitọ Ṣọọṣi CAC, Ogo Oluwa Parish, nipinlẹ Ogun, ni baba tẹ ẹ n…