Gbajumọ oṣere, Ọmọtọla Jalade, ti ko Koro o

Faith Adebola Gbajumọ oṣere ori itage nni, Ọmọtọla Jalade-Ekeinde, ti ko arun Korona to wa nita…

Oṣu mẹta ni Kọlade yoo fi dari ọkọ loju titi n’Ilọrin, oyinbo kan lo lu ni jibiti

Stephen Ajagbe, Ilọrin, Fẹsun fifi ifẹ ẹtan lu obinrin oyinbo kan ni jibiti lori ẹrọ ayelujara,…

Sanni Abacha ti tun fi biliọnu meji ataabọ naira ranṣẹ sawọn ọmọ Naijiria ‘lati ọrun’

Lati ọjọ kẹjọ, oṣu kẹfa, ọdun 1998, ti Ọgagun Sanni Abacha to ti figba kan jẹ…

Ẹ woju awọn Fulani to n da awọn eeyan lọna ni Ṣaki

Olawale Ajao, Ibadan Awọn ero to n ti Ṣaki lọ siluu Igboho lagbegbe Oke-Ogun, ni ipinlẹ…

Emi kọ ni mo pa iyawo atawọn ọmọ mi o – Oyediran (Fidio)

Ipari oṣu to kọja ni iroyin naa gbalẹ pe nọọsi kan, Solomon Tunde Oyediran, gun iyawo,…

Oloṣelu Eko, Lanre Razak, ti ku o!

Ọjọ Abamẹta, Satide, ọjọ kẹẹẹdogun, oṣu yii, ni agba oloṣelu ilu Ẹpẹ, nipinlẹ Eko, to ti…

O yẹ ki Aarẹ Buhari ko awọn igbimọ alaṣẹ rẹ wa ka jọ waa bẹ Yeye Ọṣun lori arun Korona ni- Ọṣunbiyii

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Lati igba ti ayẹyẹ ọdun Ọṣun Oṣogbo to waye lopin ọsẹ to kọja…

Itajẹsilẹ to n ṣẹlẹ lojoojumọ le fa ibinu Ọlọrun fun Naijiria-Ẹlẹbuibọn

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Araba Awo ti ilu Oṣogbo, Oloye Ifayẹmi Ẹlẹbuibọn, ti ke sijọba apapọ orileede…

Bayern lu Barca laluwo pẹlu ami-ayo mẹjọ si meji

Iya ami-ayo mẹjọ si meji ki i ṣe nnkan ti ẹgbẹ agbabọọlu Barcelona ilẹ Spain ro…

Idanwo WAEC: ọga ileewe tabi olukọ to ba ṣe eru idanwo ni Kwara yoo da ara rẹ lẹbi

 Stephen Ajagbe, Ilọrin Bawọn akẹkọọ ileewe girama ṣe n gbaradi fun idanwo aṣekagba, WAEC, to maa…

Ẹgbẹ to dara ni ẹgbẹ awa ajẹ ati emere, awọn adari ẹsin lo n ba wa lorukọ jẹ – Oyelọla Ẹlẹbuibọn

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Alakooso ẹgbẹ awọn ajẹ ati emere nipinlẹ Ọṣun, Oloye (Iyaafin) Oyelọla Ẹlẹbuibọn, ti…