Adeṣọla Ọlaniyan gbade, o di ọba ilu Ipokia tuntun

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọjọbọ, Wẹsidee, ọsẹ yii, ni Gomina ipinlẹ Ogun, Ọmọọba Dapọ Abiọdun, fun Onipokia…

Ẹ je ka bẹ Pasitọ Adeboye atawọn olori ẹlẹsin to ku, ki wọn ma ba aṣa Yoruba jẹ o

Ọjọgbọn agbaye kan, Purofẹsọ Toyin Falọla, ti sọ pe gbogbo ẹni yoowu to ba fẹran aṣa…

Adajọ ti gba beeli awakọ to pa Tolulọpẹ Arotile

Lẹyin ti ile-ẹjọ gba beeli ọmọkunrin to wa mọto, ati ẹni to ni mọto to pa…

Baba ọgọrin ọdun to fipa ba ọmọ ọdun marun-un lo pọ l’Agege loun fẹẹ fẹ ẹ ni

 Faith Adebọla Tika-tẹgbin lawọn eeyan n wo baba ẹni ọgọrin ọdun kan, Ebenezer Ọlaiya Oyewọle, nigba…

Adedeji, ayederu lọọya, n lọ sẹwọn ọdun mẹta ba a ṣe kọwe rẹ l’Abẹokuta

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta  Kootu ko fi ẹjọ ayederu lọọya kan, Adedeji Ebenezer, ẹni ti aṣiri ẹ tu…

Ewu nla ni eto Big Brother fun ọjọ iwaju awọn ọdọ wa – Ọọni Ogunwusi

Arole Oduduwa, Ọọni Adeyẹye Ẹnitan Ogunwusi ti kọminu lori iha ti awọn ọdọ orileede Naijiria kọ…

Nigba t’Abiọla atawọn eeyan rẹ kọju ija si Awolọwọ ni 1979 (Apa Kẹfa)

*Idi abajọ ree o Olori ijọba ologun igba naa, Ọgagun agba Yakubu Gowon, lo ni ki…

Oju ole ree: Lati ipinlẹ Anambra ni Chidi ati Obinna ti wa n ja ọkada gba l’Owode Yewa

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Lẹyin ti wọn ti wa si Owode Yewa lẹẹmẹta, ti wọn si ti…

Ohun to fa wahala lasiko ibo ti wọn di ni 1964 niyi o (5)

Nigba ti yoo fi di ọjọ keji ti wọn dibo 1964 yii tan, awọn ijọba orilẹ-ede Naijiria…

Ẹ gba mi o: awọn ọlopaa SARS ti ọmọ mi mọle nitori owo biribiri ti wọn fẹẹ gba ti ko fun wọn

Ile-ẹjọ giga Eko lo pariwo lọ o. Obinrin oniṣowo Eko kan, Regina Stanley ni. O pariwo…

Eemọ ree o: wọn ni gomina ilẹ Hausa kan ni olori awọn Boko Haram

Ọkunrin kan to ti fi igba kan jẹ igbakeji ọga pata ni ileefowopamọ apapọ ilẹ wa…