Faith Adebọla, Eko Laika ti pe ayẹwo ṣi n lọ lori ohun to fa iṣẹlẹ ile…
Meji to ku ninu awọn Fulani to n jale ni marosẹ Eko s’Ibadan ti bọ sọwọ ọlọpaa
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọwọ ọlọpaa ipinlẹ Ogun ti tẹ meji yooku ninu awọn ọmọde ole to…
Ẹ woju awọn ọrẹ meji yii, ayederu ọili ni wọn n ṣe, ladajọ ba ju wọn sẹwọn ọdun mẹrin l’Ekoo
Faith Adebọla, Eko Arikọgbọn ati abamọ nibi tọrọ awọn afurasi ọdaran meji tẹ ẹ n wo…
Ijọba apapọ ṣi papakọ ofurufu mẹrinla
Oluyinka Soyemi Ijọba apapọ ilẹ Naijiria ti fọwọ si ṣiṣi awọn papakọ ofurufu mẹrinla lẹyin awọn…
Awọn ọmọ iya meji ti wọn fẹẹ ṣ’oogun owo n’Ijẹbu ti pa iya arugbo o
Ni Ijẹbu Muṣin lo ti ṣẹlẹ. Awọn ọmọ iya kan naa, Akinọla Akeem ati Muyiwa Akeem…
Awọn Hausa atawọn ọmọọta n ja l’Oṣogbo o
Ija kan teeyan ko ti i gbọ hulẹhulẹ ohun to fa a gan-an bẹ silẹ laarin…
Baba Gomina Kwara, AbdulGaniyu Abdul-Razaq, jade laye lẹni ọdun mẹtalelaaadọrun-un
Stephen Ajagbe, Ilọrin Laaarọ ọjọ Abamẹta, Satidee, yii, ni ẹbi Abdulrazaq kede iku baba Gomina Kwara,…
Arotile: Wọn ti fa awọn afurasi ati mọto wọn le ọlọpaa lọwọ
Ileeṣẹ ọmọ-ogun ofururu Naijiria ti fa awọn mẹta ti wọn fẹsun kan lori iku Tolulọpẹ Arotile…
Bi iya yii ṣe maa n ju’di ẹ to ba n rin lọ lo jẹ ki n fipa ba a sun
Ki i ṣe awọn ọmọge nikan ni wọn gbọdọ maa ṣọra lati wọ aṣọ ti yoo…
Ileya: Ijọba Kwara fagi le ipejọpọ Yidi, ṣiṣi ile itaja atawọn ibudo igbafẹ lasiko ọdun
Stephen Ajagbe, Ilọrin Lati dẹkun atankalẹ arun Koronafairọọsi nipinlẹ Kwara, ijọba ti fagi le ipejọpọ ni…
Awọn eeyan ha sinu ile alaja mẹta to wo l’Ebute-Mẹta, l’Ekoo
Faith Adebọla, Eko Titi di ba a ṣe n sọ yii, ariwo ẹkun ati igbe awọn…