Nitori arun aṣekupani Koronafairọọsi to gbode kan, Awujalẹ ilẹ Ijẹbu, Ọba Sikiru Adetọna ti kede pe…
Wọn tun ti ji awọn arinrin-ajo meji gbe l’Akoko
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Iṣẹlẹ ijinigbe to n waye lagbegbe Akoko tun gbọna mi-in yọ pẹlu bi…
Gomina Abdulrazaq ṣabẹwo sileeṣẹ tẹlifiṣan NTA Ilọrin to jona
Stephen Ajagbe, Ilọrin Lalẹ ana, ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ni Gomina ipinlẹ Kwara, Abdulrazaq Abdulrahman, ṣabẹwo sileeṣẹ tẹlifiṣan tijọba apapọ, NTA,…
Ẹni tọwọ ba tẹ pe ko lo ibomu atawọn to gba wọn laaye yoo foju bale-ẹjọ ni Kwara
Stephen Ajagbe, Ilọrin Nitori bi atankalẹ arun Koronafairọọsi ṣe n fojoojumọ gbilẹ nipinlẹ Kwara, ijọba ti…
Gomina ipinlẹ Ekiti, Kayọde Fayẹmi ti ko arun Koronafairọọsi o
Gomina Kayọde Fayẹmi tipinlẹ Ekiti ti ko arun Koronafairọọsi. Gomina ọhun funra ẹ lo ṣe ikede…
O ma wa ga o, wọn tun pa ọmọ ọdun mẹrindinlogun mi-in l’Akinyẹle, n’Ibadan
Ọlawale Ajao, Ibadan Niṣe ni gbogbo eeyan ro pe iku ojiji tawọn olubi ẹda kan fi…
Ija de: Alaafin lo nilẹ ni, abi awọn ẹgbẹ ọmọlẹyin Kristi?
Ni bayii, o da bii pe ẹgbẹ awọn Kristẹni ti wọn n pe ni CAN (Christian…
O ma ṣe o, terela Dangote tun pa baba atọmọ ẹ ni Lọkọja
Ọrọ terela Dangote to paayan ni ipinẹ Ogun ni lọsẹ to kọja lawọn eeyan ṣii n…
Buhari yari, o ni, ‘E ma ba mi le awọn eeyan mi lọ!’
Aarẹ orilẹ-ede yiii, Ọgagun agba Muhammadu Buhari ti yari mọ awọn aṣofin Naijiria lọwọ bayii o,…
Akeredolu ṣabẹwo ‘ẹ ma binu’ sawọn to fidi-rẹmi ninu eto idibo abẹle
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ni ibamu pẹlu ileri to ṣe lẹyin ti wọn kede rẹ gẹgẹ bii…
Man City din dundu iya fun Watford
Oluyinka Soyemi Dundu iya ami-ayo mẹrin si odo ni Manchester United din fun Watford lalẹ yii…