Nurudeen to pa iya atawọn ọmọọmọ rẹ n’Iniṣa foju bale-ẹjọ

Florence Babaṣọla Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun  ti gbe Lukman Tijani Ọpẹyẹmi, ẹni ti ọwọ tẹ lori…

Awọn afurasi ọmọ ẹgbẹ okunkun marun-un dero ẹwọn l’Ekiti

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ọgba ẹwọn to wa niluu Ado-Ekiti, lawọn afurasi marun-un tẹ ẹ n wo…

Ọrọ ilẹ ti yanju, ẹ ba mi gbadura ki Ọlọrun falubarika si i

Ẹ wo o, ki ire Ọlọrun ma jinna si gbogbo wa. Gbogbo ohun ti a n wa yii, gbogbo…

Ki lo n ṣẹlẹ: Ijọba Buhari fẹẹ gba Amọtẹkun lọwọ awọn Yoruba!

Ọpọ eeyan ni ko ka ọrọ naa si, ṣugbọn nigba ti wọn ranti pe ọrọ ti ọlọgbọn…

Nibo lẹyin n gbe, nibo lẹyin wa: Nigba t’Abiọla atawọn eeyan rẹ kọju ija si Awolọwọ ni 1979 (9)

*Idi abajọ ree o Theophilous Akindele ko ti i pari gbolohun to n sọ lọwọ nigba…

Ọwọ ba Sunday, ọkan ninu awọn ajinigbe to pa Iya Maria n’Ijohun 

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Lẹyin ọsẹ kan ti ikọ ẹlẹni mẹrin kan ya wọ Ijohun, nijọba ibilẹ…

Ogo mi lọkọ mi n lo ti ṣọọṣi ẹ fi n kun, mi o fẹ ẹ mọ – Felicia

Ọlawale Ajao, Ibadan Niṣe lọrọ adari ṣọọṣi kan n’Ibadan, Adebayọ Bamidele, da bii igba teeyan ba…

Obinrin meji lo wa ninu awọn ikọ adigunjale ti wọn mu l’Ekiti

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti   Awọn meje kan, ninu eyi ti obinrin meji wa, ti ha sọwọ ọlọpaa…

O ṣoju mi koro (Apa keji)

Nibo la oo gbe eleyii gba o Aarẹ Ona Kakanfo ilẹ Yoruba, Aarẹ Gani Adams, sọrọ…

O ṣoju mi koro (Apa Kin-in-ni)

Ẹ sọ fun wọn ki wọn ma dan an wo Bo ba jẹ Aarẹ Muhammadu Buhari…

Emmanuel n rin ni bebe ẹwọn, foonu lo ji l’Ado-Ekiti

*Bẹẹ ni Moses to ji ọkada dero kootu Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ọmọ ọdun mọkandinlogun ni Emmanuel…