Ọlawale Ajao, Ibadan Titi di ba a ṣe n sọ yii ni awọn ọlọpaa ipinlẹ Ọyọ…
Author: admin
O ma ṣe o, wọn ba oku iya pẹlu awọn ọmọ rẹ meji ninu ṣọọbu
Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa nipinlẹ Eko ti sọ pe iwadii ti bẹrẹ lati mọ ohun to…
O di ipari oṣu Kẹfa ka too yọ owo iranwọ epo bẹntiroolu- Tinubu
Adewale Adeoye Olori orileede yii, Aarẹ Bọla Tinubu ti tan imọlẹ sọrọ to sọ ni gbara…
Lẹyin ti Makinde yọ Auxillary nipo, awọn ọmọ ẹ n da igboro ru n’Ibadan
Ọlawale Ajao, Ibadan Nitori bi gomina ipinlẹ Ọyọ, Ẹnjinnia Ṣeyi Makinde, ti tu igbimọ to n dari awọn awakọ…
Iku Timothy: Adajọ ni ki wọn lọọ yẹgi fun Adedoyin titi ti ẹmi yoo fi bọ lara rẹ
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Onidaajọ Adepele ti paṣẹ pe ki wọn yẹgi fun Dokita Rahman Adedoyin titi…
Ile-ẹjọ ni loootọ ni Adedoyin lọwọ ninu iku Timothy Adegoke
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Beeyan ba ju abẹrẹ silẹ, ketekete ni yoo maa gbọ ohun abẹrẹ…
Ẹjọ Timothy Adegoke: Idajọ n lọ lọwọ nile-ejọ giga l’Oṣogbo
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Wamuwamu lawọn agbofinro duro laaarọ ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọgbọnjọ, oṣu Karun-un, yii, siwaju…
Oludasilẹ AIT, Raymond Dokpesi, ti jade laye
Oludasilẹ ileeṣẹ redio ati tẹlifiṣan AIT, Oloye Raymond Dokpesi ti jade laye. Ọsibitu kan niluu Abuja…
A maa ṣakoso ijọba orileede yii ni, a ko ni i jẹ gaba lori araalu-Tinubu
Adewale Adeoye Aarẹ tuntun ti wọn ṣẹṣẹ bura fun lorileede yii, Aarẹ Bọla Ahmed Tinubu, ti…
A maa yọ owo iranwọ ori epo danu, aabo si maa duro digbi lasiko yii-Tinubu
Faith Adebọla Aarẹ tuntun ilẹ wa, Bọla Ahmed Tinubu, ti sọrọ lori awọn nnkan to maa…
Tinubu di aarẹ Naijiria kẹrindinlogun
Faith Adebọla Ni ba a ṣe n sọ yii, wọn ti ṣebura wọle fun Aṣiwaju Bọla…