Adefunkẹ Adebiyi, Abẹ́òkúta Ni fẹẹrẹ Ọjọbọ, ọjọ kọkanla, oṣu keji yii, lawọn Fulani ti awọn ara…
Author: Alaroye
Lẹyin tawọn Fulani pa agbe kan tan ni wọn tun dana sun oko koko rẹ n’Igangan
Ọlawale Ajao, Ibadan Awọn amòòkùṣìkà Fulani darandaran tun ti sọ̀kò ìbànújẹ sí agbagbe Ibarapa lẹẹkan sí…
Awọn to fẹẹ gba gareeji lo fa ijaagboro to ṣẹlẹ l’Ọbalende-Jimoh
Faith Adebọla, Eko Inu idarudapọ lawọn eeyan agbegbe Ọbalende ji si laaarọ kutu Ọjọbọ, Tọsidee yii,…
Ijọba ko ni i faaye gba ẹnikẹni lati ṣe iwọde kankan ni Too-Geeti Lẹkki-Lai Muhammed
Minisita fun eto iroyin nilẹ wa, Alaaji Lai Muhammed, ti sọ pe ijọba ko ni i…
Gomina ipinlẹ Eko tele, Lateef Jakande, ti ku o
Alhaji Lateef Jakande, gomina ipinlẹ Eko tẹlẹ, ti jade laye lẹni ọdún mọkanlelaaadọrun-ùn.Owurọ kutu Ọjọbọ, Tọsidee,…
Ọwọ ti tẹ Tina, ọmọ lanledi to lu tẹnanti wọn pa tori owo ina n’Ikorodu
Faith Adebọla, Eko Ahamọ ọlọpaa ni ọmọbinrin kan, Tina Essi, wa bayii latari bi wọn ṣe…
Ọlọpaa ti mu awọn Fulani to pa Alaaja Sherifat, ọga ileepo l’Ayetẹ
Ọlawale Ajao, Ibadan O kere tan, ọwọ awọn agbofinro ti tẹ marundinlogoji (35) ninu awọn afurasi…
Lasiko tawọn to ji mi gbe sun lọ fọnfọn ni mo sa mọ wọn lọwọ loruganjọ- Atẹrẹ
Stephen Ajagbe, Ilorin Baale ile ẹni ọdun mẹrindinlaaadọta, Alhaji Musa Garba Atẹrẹ, tawọn ajinigbe ji gbe…
Ẹwọn n run nimu Yusuf o, ọmọ bibi inu ẹ lo binu ju sodo ni Badagry
Faith Adebọla, Eko Eebu ati epe loriṣiiriṣii lawọn eeyan n ṣẹ le baba ẹni ọdun mẹtadinlọgbọn…
Ọwọ tẹ ọkọ to fẹẹ ba’yawo rẹ ṣedanwo igbaniwọle awọn olukọ l’Ọṣun
Florence Babaṣọla Ọwọ awọn ikọ Sifu Difẹnsi ti tẹ ọkunrin kan, Adekunle Arẹmu, lori ẹsun pe…
O maa n wu mi bawọn ẹgbẹ mi ṣe n sọ, ati ka ede oyinbo, lo jẹ ki n pada sileewe – Fọlaṣade
Stephen Ajagbe, Ilorin Iyaale ile ẹni ọdun mejidinlogoji kan, Ajayi Fọlaṣade, to wa ni kilaasi JSS2,…