Ijọba ko gba ẹbẹ CAN l’Ogun, wọn ni ko saaye ṣọọṣi, konikaluku ṣe aisun ọdun nile ẹ ni

Adefunke Adebiyi, Abeokuta Ẹbẹ ti ẹgbẹ Onigbagbọ lorilẹ -ede yii, (CAN), ẹ̀ka tipinlẹ Ogun, bẹ Gomina…

Ki laa ti waa ṣeyi si, wọn tun ji agbẹ kan gbe ninu oko ẹ n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Inu ibẹru-bojo ikọlu awọn ajinigbe lawọn agbẹ agbegbe Moniya, niluu Ibadan, wa bayii,…

Boya ni Tọpẹ ko ni i ṣẹwọn o, ẹni to fẹẹ ja lole lo jan irin mọ lori l’Oṣogbo

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Tọpẹ Ọlọmọla, ẹni ogun ọdun, ni adajọ ile-ẹjọ Majisreeti ilu Oṣogbo ti ju…

Adigunjale atawọn Amọtẹkun doju ibọn kọra wọn l’Ọyọọ

Ọlawale Ajao, Ibadan Bii igba ti wọn wa loju ogun lọrọ ri laarin ikọ eleto aabo…

Ijọba ipinlẹ Ọṣun pohun da, o ni kawọn Kristiẹni ṣe isin aisun ọdun tuntun, ṣugbọn …

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Lẹyin ọpọlọpọ ifikunlukun, ijọba ipinlẹ Ọṣun ti fun awọn Onigbagbọ lanfaani lati ṣe…

Eyi ni bi onilu Ayinla Ọmọwura, Adewọle Alao, ṣe ku gan-an

Jide Alabi ati Adefunkẹ Adebiyi Laṣaalẹ ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọjọ kọkandinlọgbọn, oṣu kejila, ọdun 2020, ni…

 Adewọle Alao, onilu Ayinla Ọmọwura, ti ku o

Jide Alabi Lẹyin bii ọjọ meloo kan ti awọn ẹgbẹ Ayinla Ọmọwura lori ẹrọ ayelujara ṣe…

Ko sidii fun Naijiria lati toṣi- Ọbasanjọ 

Faith Adebọla “Ọlọrun kọ lo jẹbi ohun to n ṣẹlẹ si wa lorileede yii, awa funra…

Nitori Korona: Ijọ Ridiimu fagi le isin aisun-ọdun tuntun

Jide Alabi Ijọ Ridiimu ti sọ pe ko ni i si anfaani lati kora jọ papọ…

 Ijọba Ondo kilọ fun ẹgbẹ CAN: Ẹni to ba ṣe isọ-oru wọnu ọdun tuntun n fẹwọn ṣere.

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ijọba ipinlẹ Ondo ti fa ibinu nla yọ latari ọrọ ti Alaga ẹgbẹ…

 Eyi ni bi wọn ṣe pa awọn obinrin meji laarin ọjọ kan ṣoṣo l’Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ki i ṣe ibẹru kekere niṣẹlẹ iku awọn obinrin meji kan ti wọn…