Bọjẹẹti 2021 ti dofin o, Aarẹ Buhari ti buwọ lu u l’Abuja

Faith Adebọla Eto iṣuna owo tijọba apapọ maa na lori iṣejọba lọdun 2021 ti kuro ni…

Ọdun ku dẹdẹ ko pari, ọmọ Mọla gun iyaale ile pa l’Ekoo

Bo ti ku dẹdẹ ki ọdun 2020 yii pari ni obinrin oniṣowo kan, Chirsty Mmakwe, pade…

Wọn ti sinku Adewọle Onilu-Ọla

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Irọlẹ Ọjọruu, Wẹsidee, ọgbọnjọ, oṣu kejila yii,  ni wọn sinku Oloogbe AbdulRahman Adewọle Alao Onilu-ọla,…

Awọn olukọ tijọba le danu fẹhonu han ni Kwara

Stephen Ajagbe, Ilorin Awọn olukọ to le ni ẹgbẹrun meji tijọba ana gba sẹnu iṣẹ lọdun…

Korona ti tan ka ijọba ibilẹ mẹẹẹdogun, eeyan mẹrindinlogoji lo tun ti mu ni Kwara

Stephen Ajagbe, Ilorin Eeyan mẹrindinlogoji lo tun ko arun Koronafairọọsi l’ọgbọn, oṣu kejila, ọdun yii, nipinlẹ…

Awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun ‘Aye’ to n daamu wọn n’Ijẹbu-Ode bọ sọwọ fijilante

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Ọjọruu, ọgbọnjọ, oṣu kejila yii, ki i ṣe ọjọ ire fawọn ọmọ ẹgbẹ okunkun…

Nitori aala ilẹ, wọn lu Rasak pa l’Ọbafẹmi-Owode

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Awọn ọlọpaa ipinlẹ Ogun ti mu awọn mẹta kan, Idowu Shorunkẹ, Daniel  Ikwe ati Micheal…

Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun ti ni kọmiṣanna tuntun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Wọn ti gbe kọmisanna tuntun wa fun ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun. Orukọ rẹ…

Dapọ Abiọdun buwọ lu aba iṣuna ọdun 2021

 Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Gomina ipinlẹ Ogun, Ọmọọba Dapọ Abiọdun, ti buwọ lu aba iṣuna ọdun 2021. Ile…

Afẹnifẹre ko ti i fọwọ si ipo Aarẹ fun Tinubu, Fayẹmi, tabi Tunde Bakare- Yinka Odumakin

Lati tan imọle si awuyewuye to gbode kan lori ẹni ti awọn Yoruba yoo fa kalẹ…

Ọmọ Ibo kan wọ wahala l’Ekiti, obinrin lo ge lọmu jẹ

Aderounmu Kazeem Nile ẹjọ majisireeti, kan niluu Ado Ekiti, lọkunrin ọmọ Ibo kan ti n ṣalaye…