Lasiko ti Lekan fẹẹ fọle onile lo bọ sọwọ awọn agbofinro n’Ibẹju-Lẹkki

Faith Adebọla, Eko Ori lo ko awọn olugbe ile kan lagbegbe Ibẹju-Lẹkki, nipinlẹ Eko, yọ, diẹ…

Ọwọ ọlọpaa tẹ mẹrinla ninu awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun to n yọ wọn lẹnu n’Ikorodu

Faith Adebọla, Eko Mẹrinla lara awọn afurasi ọmọ ẹgbẹ okunkun ‘Aiye’ to n da wahala silẹ…

Awọn tọọgi kọju ija sira wọn l’Ejigbo, ni wọn ba yinbọn pa Abeeb

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọmọdekunrin kan, Abeeb Abifarin, lo ti jẹ Ọlọrun nipe laago mẹjọ ku diẹ…

Awọn aṣofin Eko buwọ lu eto iṣuna ọdun 2021

Faith Adebọla, Eko  Ile-igbimọ aṣofin ipinlẹ Eko ti buwọ lu tiriliọnu kan, miliọnu mẹtalelọgọjọ naira (#1.163…

Nitori ere asapajude, ajọ ẹsọ oju popo mu mọto akero marundinlogoji

Jide Alabi Ileeṣẹ ijọba to n mojuto irinna ọkọ loju popo (FRSC), Ọgbẹni Oluṣẹgun Ogungbemide, ti…

Awọn aṣofin ti bura fun Ọbafẹmi to gba’po Tunde Buraimọh l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko Nibi ijokoo wọn to gbẹyin lọdun yii, lawọn aṣofin Eko ti bura fun…

Aago mọkanla alẹ ni ki gbogbo ṣọọṣi pari isin aisun ọdun tuntun l’Ekoo – CAN

Faith Adebọla, Eko Ẹgbẹ awọn ẹlẹsin Kristẹni, Christian Association of Nigeria, (CAN), ẹka ti Eko, ti…

Alaga ẹgbẹ oṣelu Labour, Alaaji Abdulsalam, ti ku o

Faith Adebọla  Alaga apapọ fun ẹgbẹ Labour Party, Alaaji Abdulkadir Abdulsalam, ti dagbere faye.  Owurọ ọjọ…

Ọwọ ọlọpaa tẹ ọkan ninu awọn to dana sun eeyan meji n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Ki wọn maa dana sun eeyan ti waa fẹẹ di aṣa awọn araalu…

Awọn ọba Akoko gba ijọba nimọran lori eto aabo to mẹhẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Awọn ọba alade kan l’Akoko ti pa ẹnu pọ lati gba ijọba apapọ…

Happiness tawọn ajinigbe ji l’Ekiti ti gba ominira

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ọkunrin kan tawọn ajinigbe ji lọjọ ọdun Keresi, Happiness Ajayi, ti gba ominira…