Nitori bawọn Hausa mejidinlaaadọsan-an ṣe tun ya wọn Ondo, Amọtẹkun kilọ fawọn eeyan ilẹ Yoruba

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ẹṣọ Amọtẹkun ipinlẹ Ondo ti kilọ fawọn eeyan to wa lawọn ipinlẹ to…

Ọsẹ kan lẹyin t’Ogbomọṣọ, awọn Fulani tun pa ẹṣọ alaabo lotẹẹli l’Abẹokuta, wọn, wọn ji ẹni kan gbe

Gbenga Amos, Ogun  Ọṣẹ buruku tawọn agbebọn afẹmiṣofo gun le nilẹ Yoruba ti bẹrẹ si i…

Igbẹjọ yoo bẹrẹ lori ẹsun ayederu iwe-ẹri ti wọn ni Tinubu n ko kiri

Faith Adebọla, Eko  Ile-ẹjọ giga apapọ kan to fikalẹ siluu Abuja, olu-ilu ilẹ wa, ti pinnu…

Eyi ni bi mo ṣe sa kuro lakata awọn ajinigbe to mu mi-Ademọla 

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ọkunrin ẹni ọdun mejidinlaaadọta kan, Ọgbẹni Ademọla Adeẹkọ, ti ori ṣẹṣẹ ko yọ…

Nitori to fẹẹ da awọn ileewe ijọ ẹlẹsin pada fun wọn, MURIC gbe Makinde ṣepe

Ọlawale Ajao, Ibadan Ẹgbẹ kan to n ja fun ẹtọ awọn Musulumi, Muslim Right Concern, MURIC,…

Awọn ọlọpaa ti mu Raṣidi Ọkọ’lu, ogbologboo tọọgi to n yọ awọn eeyan ilu Ẹdẹ lẹnu

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Lẹyin oṣu marun-un ti ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun ti kede pe awọn n…

Usman so iyawo ile mọlẹ fodidi ọsẹ meji ni Kwara, o ni ajẹ ni 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ile-ẹjọ Magistreeti kan niluu Ilọrin, ti paṣẹ ki wọn sọ baale ile kan,…

Awọn agbebọn pa Tajudeen atọmọ rẹ siwaju ṣọọbu iyawo rẹ l’Oṣogbo

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ere aṣapajude lawọn ọlọja atawọn ti wọn n kọja lagbegbe Okeejẹtu, ni Garaaji…

‘Lori ọrọ eto aabo, ẹ jẹ ki Buhari lọọ sinmi sile’

Monisọla Saka Alaṣẹ ileeṣẹ redio RadioNow, Kadaria Ahmed, ti sọ pe ti Aarẹ Muhammadu Buhari ba…

Ayọdeji ti jẹwọ o: Latigba ti ọmọ mi ti wa ni ọdun meje ni mo ti n ba a lo pọ, iṣẹ eṣu ni

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Baale ile kan to tun jẹ ọdẹ aṣọde, Arowolo Ayọdeji, ẹni ọdun marundinlọgọta…

Eyi ni ba a ṣe ṣawari ọgọọrọ awọn Hausa/Fulani to fẹẹ ya wọ ipinlẹ Ondo pẹlu ọpọlọpọ oogun abẹnugọngọ-Ẹṣọ Amọtẹkun

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọgọọrọ awọn eeyan kan lati agbegbe Oke-Ọya, lawọn ẹṣọ Amọtẹkun ṣawari l’Ọjọbọ, Tọsidee,…