Ibo Gomina Ogun 2023: Awọn ọba Yewa ni Dapọ Abiọdun lawọn n ba lọ o

Gbenga Amọs, Ogun Awọn ọba alaye lorigun mẹrẹẹrin ilẹ Yewa, ni ẹkun idibo apapọ Iwọ-Oorun ipinlẹ…

Ọwọ tẹ awọn Fulani ti wọn n ji awọn eeyan gbe l’Akoko

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Awọn afurasi meje lọwọ ẹsọ Amọtẹkun ipinlẹ Ondo ti tẹ latari ijinigbe to…

Wọn ti wọ Jacob at’ọrẹ ẹ to n ṣẹgbẹ okunkun l’Ọrẹ lọ sile-ẹjọ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun meji tọwọ tẹ niluu Okitipupa lọsẹ to kọja yii,…

Ere itiju ni ẹgbẹ APC yoo gba pada bọ nile-ẹjọ ti wọn gbe mi lọ-Adeleke

Gomina tuntun ti wọn ṣẹṣẹ dibo yan nipinlẹ Ọṣun, Sẹnetọ Ademọla Adeleke, lọjọ Abamẹta, Satide, to…

Ọga ọlọpaa patapata paṣẹ eto aabo to rinlẹ kaakiri awọn ileewe 

Monisọla Saka, Eko Lọjọ Aiku, Sannde, ọsẹ yii, ni Ọga ọlọpaa patapata lorilẹ-ede yii, Usman Baba,…

Ọwọ awọn ṣọja tun tẹ afurasi meji mi-in ti wọn lọwọ ninu ikọlu Ọwọ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọwọ ologun orile-ede yii ti tun tẹ awọn afurasi meji mi-in lori ikọlu…

Nitori ẹsun janduku, wọn wọ ọba alaye lọ si ile-ẹjọ ni Kwara

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin L’Ọjọruu, Wẹsidee, ọsẹ yii, ni wọn wọ ọba tilu Samora, nijọba ibilẹ Irẹpọdun,…

Ọlaiya dọbalẹ, o yi gbiiri, nigba ti MC Oluọmọ fun un ni kọkọrọ mọto tuntun

Jọkẹ Amọri Bii ala ni ọrọ naa ri loju gbajugbaja elere ori-itage nni, Oloye Ẹbun Ọlaiya,…

 Nitori owo, Kamalideen gun alaamojuto ibi ti wọn ti n ta tẹtẹ pa ni Badagry

Monisọla Saka Ọkunrin ẹni ọdun marundinlogoji (35) kan, Kamalideen Raji, lọwọ awọn agbofinro ti tẹ fun…

Eeyan mẹta ku, ọpọ fara pa, nibi ija agba awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun n’Ilọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin L’Ọjọ Aje, Mọnde, ọsẹ yii, ni ọrọ di bo o lọ o yago…

Wọn ti mu marun-un ninu awọn apaayan to kọ lu ṣọọṣi Katoliiki Ọwọ lọjọsi

Faith Adebọla Ileeṣẹ ologun ilẹ wa ti kede pe ọwọ awọn ti tẹ awọn afẹmiṣofo ti…