O ku ọjọ diẹ ki ọmọ mi ṣọjọọbi lawọn apaniṣowo pa a mọ mi lọwọ- Baba akẹkọọ MAPOLY

Ọlawale Ajao, Ibadan, Gbenga Amos, Ogun Niṣe lomi le roro loju Alakooso agba ileewe gbogboniṣe Moshood Abiọla…

Ọlọpaa ti mu Adekunle to kọwe pe oun fẹẹ waa ji awọn akẹkọọ fasiti kan gbe l’Ọyọọ

Ọlawale Ajao, Ibadan Ọkan ninu awọn afurasi ajinigbe to n fooro ẹmi awọn eeyan lagbegbe Ọyọ,…

Awọn ọlọpaa ti mu ọmọbinrin ti ọrẹkunrin ẹ ku sinu otẹẹli ti wọn jọ sun mọju

Monisọla Saka Ọmọbinrin kan ni wọn lo ti ko si wahala lẹyin to rinrin-ajo wa si…

 Ọwọ ba Sanni Gafar, afurasi afẹmiṣofo to mura bii obinrin n’Ijọra

Monisọla Saka Ori lo ko Sanni Gafar, ọkunrin ẹni ọdun mọkandinlọgbọn (29), kan yọ lọwọ awọn…

Alaga ẹgbẹ PDP pariwo: Ẹ ma da wọn lohun, mi o fipo mi silẹ

Faith Adebọla  Ariwo to kọkọ gbode kan lori ẹrọ ayelujara lọjọ Aje, Mọnde, ọjọ kẹẹẹdogun, oṣu…

Inu ori ẹja gbigbẹ ni ọkunrin yii tọju oogun oloro si tọwọ NDLEA fi ba a

Monisọla Saka Ajọ to n gbogun ti ilokulo oogun ati ṣiṣe owo oogun oloro nilẹ yii,…

Iha aibikita ti Aarẹ Buhari kọ si awọn ipenija orileede yii lo n ṣakoba fun wa – Gani Adams

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Alakooso apapọ fun ẹgbẹ Oodua Peoples Congress (OPC), Iba Gani Adams, ti ke…

Nitori tiyẹn ni ko ma mu igbo mọ, Vincent binu du iya-iya rẹ bii eran l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Iya ẹni aadọrin ọdun kan ti pade iku ojiji lati ọwọ ọmọ-ọmọ rẹ,…

Awọn alatilẹyin oludije funpo aarẹ kan fiku halẹ mọ mi – Mista Macaroni

Faith Adebọla, Eko  Gbajugbaju adẹrin-in poṣonu nni, Debọ Adedayọ, ti ọpọ eeyan mọ si Misita Macaroni…

Lẹyin ti Ọlaniyi tẹwọn de lo tun lọọ fọ ṣọọbu l’Ẹdẹ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun ti tẹ ọmọkunrin ẹni ọdun mejilelogun kan, Akintunde…

Ajọ eleto idibo Ọṣun kede ọjọ ti idibo ijọba ibilẹ yoo waye

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ajọ to n ṣe kokaari eto idibo ijọba ibilẹ nipinlẹ Ọṣun, Osun State…