Ẹ ma jẹ ka fẹtanu ṣoṣelu mọ, ọjọ-ọla orileede yii ni ka ro- Dapọ Abiọdun

Gbenga Amos, Ogun “Ẹ jẹ ki n lo anfaani yii lati sọ fawọn eeyan wa pe…

Dandan ni ki APC bori ibo 2023, a o fẹẹ pẹjọ rara – Adamu

Faith Adebọla Alaga ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress, APC, Sẹnetọ Abdullahi Adamu, ti sọ pe dandan…

Ọdẹ adugbo yinbọn pa mẹkaniiki, wọn tun ji owo ẹ lọ l’Oṣogbo

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọmọkunrin atọkọṣe kan, Mohammed Badmus, ẹni ogoji ọdun, ni ọdẹ adugbo Ibuowo Estate,…

Nitori Ọbabinrin Elizabeth, awọn aye n bu Tọpẹ Alabi   

Faith Adebọla, Eko Titi dasiko yii ni oriṣiiriṣii ọrọ idaro, ibanikẹdun ati oriyin n rọjọ nilẹ…

Idi ti mo fi lu baba mi pa niyi-Hassan

Ibrahim Alagunmu Akolo ọlọpaa ipinlẹ Kwara, ni gende ẹni ọdun mejilelọgbọn kan, Ibrahim Hassan, wa bayii, latari…

Ẹya Yoruba la n ba lọ, ẹ fun wa lẹtọọ wa – Ẹgbẹ Yoruba parapọ Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin L’Ọjọbọ, Tọsidee, ọsẹ yii, ni ẹgbẹ Yoruba parapọ ni Kwara, rọ ijọba apapọ…

Awọn ọmọ Hausa yii lọọ ji waya ina tu n’Ikoyi

Faith Adebọla, Eko Marun-un ni wọn, Yẹkinni Mohammed, ẹni ọdun mejilelaaadọta, Mukaila Tukur, ẹni ọdun mejilelogoji,…

Awọn kọsitọọmu gbẹsẹ-le ‘kinni’ kẹtẹkẹtẹ tawọn kan n ko lọ siluu oyinbo  

Monisọla Saka Oriṣiiriṣii lọna lawọn eeyan wa n gba wa owo bayii, igbo, kokeeni atawọn egboogi…

Ọjọgbọn Ẹgbẹwọle di ọga agba tuntun fun Fasiti Ilọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin L’Ọjọbọ, Tọsidee, ọsẹ yii, ni awọn alaṣẹ Fasiti Ilọrin, nipinlẹ Kwara, kede Ọjọgbọn…

Ọbabinrin Elizabeth Keji ti ku o!

  Faith Adebọla Elizabeth keji, ọbabinrin to pẹ lori itẹ ju lọ lorileede United Kingdom, ti…

 Rasaki atọrẹ ẹ n rin ni bebe ẹwọn, ewurẹ ni wọn lọọ ji ko ni Ijan-Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ọwọ ẹṣọ Amọtẹkun ipinlẹ Ekiti ti tẹ ọkunrin tẹwọnde kan, Basiru Rasaki, ẹni…