Ibo 2023: Ki Musulumi jẹ aarẹ ati igbakeji ẹ ko le ṣiṣẹ – Gumi

Faith Adebọla, Eko Ilumọ-ọn-ka olukọ ẹsin Musulumu lapa Oke-Ọya ilẹ wa, Sheikh Ahmad Abubakar Gumi, ti…

Ẹya ara ọkọ lawọn eleyii n ji tu ni Surulere tọwọ fi ba wọn

Faith Adebọla, Eko  Ẹya ara ọkọ, agaga kinni kan to wa nibi agbari awọn ọkọ ode-oni…

Ọmọọba ran awọn agbanipa si Kabiyesi Ọja-Ọdan

Gbenga Amọs, Ogun Awọn afurasi ọdaran ọmọ ẹgbẹ okunkun mẹfa tọwọ ba lagbegbe Ọja-Ọdan, nipinlẹ Ogun,…

Ọwọ tẹ Ifẹdayọ nibi to ti fẹẹ ji ọmọ meji gbe l’Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọwọ ẹṣọ Amọtẹkun ipinlẹ Ondo ti tẹ ọkunrin ọlọkada kan, Ifẹdayọ Oluwadunsin, nibi…

Ikunlẹ abiyamọ o! Fẹnsi ileewe wo pa ọmọde meji l’Amukoko

Faith Adebọla, Eko Awọn ọmọde meji kan, Samat, ọmọọdun mẹsan-an, ati ẹni keji, Saheed, ti wọn…

Ọlọpaa bẹrẹ iwadii lori ọmọ ọdun mọkandinlogun to pokunso niluu Ileṣa

 Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun ti bẹrẹ iwadii lori iku ọmọdekunrin ẹni ọdun mọkandinlogun…

O ma waa ga o! Ṣẹgun naa tun fipa ba ọmọ bibi inu ẹ laṣepọ l’Abẹokuta

Gbenga Amos, Ogun  Epe rabandẹ rabandẹ lawọn eeyan n gbe baale ile ẹni ọdun mẹrindinlọgọta yii,…

EFCC ti mu oyinbo Chinese to n wakusa lọna aitọ n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin   Ajọ to n gbogun ti iwa jibiti ati ṣiṣe owo ilu mọkumọku nilẹ…

Ẹ wo Oluwaṣeun to n fibọn onike jale n’Idiroko

Gbenga Amos, Ogun Ọjọ gbogbo ni tole, ọjọ kan ni tolohun. O pẹ ti ọdọkunrin ẹni…

Ẹyin ọkunrin gidi da, Ẹniọla Badmus loun n w’ọkọ o

Faith Adebọla, Eko Bawọn apọn ti wọn n wa iyawo, atawọn ọkunrin ti wọn n ṣaroye…

O ma ṣe o, kọntena tẹ ọmọọdun mẹfa pa sibudokọ Iyana Isọlọ

Faith Adebọla, Eko Ọmọ meji, tẹgbọn-taburo, ni baba kan fa lọwọ nigba to n jade nile…