Iṣẹ ti wọn yan fun INEC lati ṣe labẹ ofin ju agbara wa lọ – Yakubu

Faith Adebọla, Eko Ọga agba ajọ INEC to n ṣe kokaari eto idibo nilẹ wa (Independent…

Baba Ijẹṣa pẹjọ ko-tẹ-mi-lọrun, o ni ki wọn foun ni beeli lẹwọn

Faith Adebọla, Eko Ọjọ Aje, Mọnde, ọsẹ to n bọ yii, ni ile-ẹjọ akanṣe to n…

Awọn eeyan ba Akeredolu daro lori iku iya rẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọkan-o-jọkan awọn ọrọ ibanikẹdun lawọn eeyan ti n fi  ranṣẹ si Gomina ipinlẹ…

Akẹkọọ mẹfa la ti ni ki wọn lọọ rọọkun nile lori ẹsun iwa ibajẹ – Ọga Fasiti Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọga agba Fasiti Ọṣun, Osun State University, Ọjọgbọn Ọdunayọ Clement Adebọoye, ti sọ…

Ipo Alaafin da wahala silẹ laarin awọn ọmọọba

Ọlawale Ajao, Ibadan Pẹlu bi nnkan ṣe n lọ yii, afaimọ ni eto lati yan Alaafin…

Awọn adigunjale ya bo ile-ijọsin n’llọrin, wọn ji ọpọlọpọ dukia pasitọ lọ

  Ibrahim Alagunmu, Ilọrin L’Ọjọ Aje, Mọnde, ọsẹ yii, ni awọn afurasi adigunjale kan ya bo…

Makinde gba Atiku lalejo n’Ibadan, o ni dandan ni ki Ayu fipo silẹ

Ọlawale Ajao, Ibadan Ni nnkan bii aago mejila ku iṣẹju diẹ ni oludije funpo aarẹ lorukọ…

Olowu Kuta rawọ ẹbẹ sijọba apapọ lati yanju ọrọ iyanṣẹlodi ASSU kiakia

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọba Adekunle Makama Oyelude, Tẹgbosun Kẹta, ti i ṣe Olowu ti ilu Kuta,…

Lasiko ti wọn fẹẹ gbowo itusilẹ, ẹṣọ alaabo mu awọn ajinigbe meji balẹ ni Kwara   

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin  Ileeṣẹ ọlọpaa pẹlu ifọwọsowọpọ ẹgbẹ fijilante, ni Kwara, ti doola ẹmi iya atọmọ…

Ijọba mi ti le awọn afẹmiṣofo danu, a tun pese ohun amayedẹrun faraalu-Buhari

Jọkẹ Amọri Nitori pe gbogbo awọn to yẹ ko sọ ọ ko le sọ ọ, mi…

Ibo 2023: Ki Musulumi jẹ aarẹ ati igbakeji ẹ ko le ṣiṣẹ – Gumi

Faith Adebọla, Eko Ilumọ-ọn-ka olukọ ẹsin Musulumu lapa Oke-Ọya ilẹ wa, Sheikh Ahmad Abubakar Gumi, ti…