Oludamọran Fayẹmi lori eto oṣelu kọwe fipo silẹ, o darapọ mo ẹgbẹ SDP

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Oludamọran agba lori ọrọ to jẹ mọ eto idibo fun Gomina Kayọde Fayẹmi…

Nitori eto idibo ipinlẹ Ekiti, Ọṣun Akintoye wọ ajọ INEC lọ sile-ẹjọ

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ẹgbẹ Ilana Ọmọ Oodua nile loko, ti Ọjọgbọn Banji Akintoye jẹ adari rẹ,…

Eyi ni bawọn ẹlẹgbẹ okunkun ṣe pa Tommy l’Abẹokuta

Gbenga Amos, Abẹokuta Titi di ba a ṣe n sọ yii, inu ibẹrubojo lawọn olugbe agbegbe…

Ọlọpaa to n halẹ m’awọn ti mọto wọn ni gilaasi tintẹẹdi l’Ekoo ti n kawọ pọnyin rojọ

Faith Adebọla, Eko  Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko ti mu Inspẹkitọ Dele Reuben, ọlọpaa to fooro ẹmi…

Chidinma ṣe pati daran, wọn sọ ọ sẹwọn ọdun meji tori bẹntiroolu to ha fawọn alejo ẹ

Faith Adebọla, Eko  Ṣẹ ẹ ranti obinrin alafẹ ilu Eko, Chidinma Pearl Ogbulu, tọrọ pati rẹ…

Alele-Williams, obinrin akọkọ to jẹ ọga agba fasiti ni Naijiria, jade laye

Faith Adebọla  Abilekọ Grace Alele-Williams, obinrin to fitan balẹ lọdun 1985 gẹgẹ bii ọga agba fasiti…

INEC gbe orukọ awọn ti yoo dije funpo gomina nipinlẹ Ọṣun jade

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Nigbaaradi fun idibo gomina ipinlẹ Ọṣun ti yoo waye lọjọ kẹrindinlogun, oṣu Keje,…

Ẹgbẹ APC ipinlẹ Ọyọ fọ si meji, wọn yan alaga mi-in lẹyin Ọmọdewu

Ọlawale Ajao Ibadan Lẹyin ti ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress, APC, ti yan alaga apapọ wọn lai…

Igbakeji olori ileegbimọ aṣoju-ṣofin ilẹ wa tẹlẹ, Lasun Yusuf, fi ẹgbẹ APC silẹ l’Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọkan lara awọn to dije ninu idibo abẹle funpo gomina labẹ asia ẹgbẹ…

Lasiko ti mo wa lọgba ẹwọn ni wọn fun mi ni nọmba ikọ adigunjale ti mo darapọ mọ yii-Abiọdun

Gbenga Amos, Abẹokuta “Awọn adigunjale to n ṣọṣẹ nipinlẹ Ogun yii, Eko ni wọn ti n…

Ile-ẹjọ ti ni ki Adekọla maa lọ sẹwọn o, iya ati aburo rẹ lo pa ni Kwara

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ile-ẹjọ Magistreeti kan to wa niluu Ilọrin, nipinlẹ Kwara, ti sọ pe ki…