Ija awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun: Dapọ Abiọdun ni kawọn agbofinro rọ lọ si Ṣagamu

Gbenga Amos, Abẹokuta. Latari akọlu awọn ẹlẹgbẹ okunkun to waye lọjọ Aje, Mọnde, ọsẹ yii. Gomina…

Akẹkọọ Fasiti Ifẹ: Adajọ ni Adedoyin atawọn oṣiṣẹ rẹ lẹjọ lati jẹ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Adajọ ile-ẹjọ giga ipinlẹ Ọṣun, Onidaajọ Adebọla Adepele Ojo, ti sọ pe Dokita…

O ma ṣe o, dokita ti wọn yinbọn fun lasiko tawọn afẹmiṣofo kọ lu reluwee to n lọ lati Abuja si Kaduna ti ku o  

Jọkẹ Amọri Ọkan ninu awọn ti wọn ṣakọlu si lasiko ti awọn afẹmiṣofo kọ lu reluwee…

Naijiria nikan kọ lounjẹ ti gbowo lori, o wọn l’Amẹrika ati UK naa – Lai Mohammed

Faith Adebọla  Ijọba Naijiria ti sọ pe ẹtan lasan lo wa nidii bawọn eeyan ṣe n…

Ipo aarẹ ko tọ sẹnikẹni to ba ti ju aadọrin ọdun lọ ni Naijiria – Ortom

Gbenga Amos “Ẹ wo awọn eeyan atata mẹta yii, ẹ wo wọn kẹ ẹ tun wọn…

Awọn agbebọ lọọ ka wọn mọle loru labule kan ni Kaduna, eeyan mẹẹẹdogun ni wọn pa

Faith Adebọla Ẹlẹkọ ọrun to n polowo nipinlẹ Kaduna lasiko yii ko sinmi rara, niṣe nipinlẹ…

Nitori ọrọ ti o to nnkan, Ridwan gun ọrẹ rẹ pa n’llọrin

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Aje, Mọnde, ọṣẹ yii, ni gende-kunrin kan, Ọgbẹni Ridwan Akintunde, gun ọrẹ…

Ija awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun: Wọn tun paayan mẹjọ ni Sagamu

Gbemiga Amọs, Abẹokuta Ija ajaku akata to n lọ laarin awọn ọmọ ẹlẹgbẹ okunkun nipinlẹ Ogun…

Adajọ ni ki wọn maa ko Kyari atawọn ọmọọṣẹ rẹ lọ si ọgba ẹwọn Kuje

Ọrẹoluwa Adedeji Ile-ẹjọ giga kan niluu Abuja ti paṣẹ pe ki wọn taari Igbakeji kọmiṣanna ọlọpaa…

Ganiyat purọ f’ọkọ ẹ pe oun loyun, lo ba lọọ ji ọmọ ọjọ mẹfa gbe l’Oṣogbo

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọmọbinrin ẹni ogoji ọdun kan, Ganiyat Abass, lo ti n ka boroboro ni…

Emi ni ẹgbẹ APC maa fa kalẹ lati dupo aarẹ lọdun 2023-Yahaya Bello

Jọkẹ Amọri Bo tilẹ jẹ pe agbegbe kan naa ni Abdullahi Adamu ti wọn ṣẹṣẹ yan…