Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ileeṣẹ aṣọbode ilẹ wa, ẹka ‘Ogun 1 Area Command’, ti ni awọn kabaamọ…
Category: Ìròyìn
Gomina Seyi Makinde wọle pade pẹlu Ladọja, Lekan Balogun atawọn agba oye Ibadan
Ni Satide, ọjọ kẹẹẹdogun, oṣu kin-in-ni, ọdun yii, ni Gomina ipinlẹ Ọyọ, Ẹnjinnia Ṣeyi Makinde, tilẹkun…
Nitori to ṣe agbere, wọn fun iyaale ile lẹgba ọgọrun-un
Ọbẹ ti baale ile ki i jẹ, iyaale ile ko gbọdọ se e ni ọrọ wọn…
Eyi ni bi Akala ṣe fa mi goke laarin awọn olorin- Ayefẹlẹ
Ọlawale Ajao, Ibadan Gbajugbaja olorin Juju nni, Dokita Yinka Ayefẹlẹ, ti ṣalaye bi gomina ipinlẹ Ọyọ…
Mo maa n jẹ ẹya ara eeyan bii nnkan ọmọkunrin, oju, ifun ati gogongo, mo si tun maa n ta a fawọn to ba fẹ-Aminu
Aminu Baba lọkunrin to jokoo yii n jẹ, ẹnu ara ẹ lo fi jẹwọ pe oun…
Nitori ẹbun mọto tawọn ọmọ rẹ fun un lọjọọbi ẹ, Iya Fẹmi Adebayọ bu sẹkun
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Inu ẹni ki i dun ka pa a mọra, koda, eeyan a maa…
Lẹyin tawọn Fulani yii sa lọgba ẹwọn Abolongo lọwọ tẹ wọn n’Isẹyin
Olu-Theo Omolohun, Oke-Ogun. Aṣeyọri nla ni fawọn ẹṣọ fijilante ilu Isẹyin, lagbegbe Oke-Ogun, nipinlẹ Ọyọ, latari bọwọ wọn ṣe…
Isọkusọ ọrọ ni pe mo ti fọwọ si Tinubu lati dupo aarẹ – Wọle Ṣoyinka
Faith Adebọla, Eko Onigege ara akọwe-kọwura ilẹ wa nni, Ọjọgbọn Wọle Ṣoyinka, ti sọ pe ọrọkọrọ…
Loootọ lẹgbẹ APC ti pin si meji l’Ọṣun, ṣugbọn TOP ni mi tọkantọkan-Arẹgbẹṣọla
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Gomina ipinlẹ Ọṣun nigba kan ri, Ọgbẹni Rauf Arẹgbẹṣọla, ti sọ gbangba pe…
Eyi ni ileri ti Akala ṣe fun mi ko too ku- Makinde
Ọlawale Ajao, Ibadan ‘‘Ọtunba Adebayọ Alao-Akala, gomina ipinlẹ Ọyọ to doloogbe ti iṣeleri lati ṣiṣọ loju…
Funra ijọba Ogun ni yoo yi ero rẹ pada nigba ti wọn ba n ri esi ofin ti wọn ṣe lori ọba sinsin l’Ogun-Ọba Ogboni Agba
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Laipẹ yii ni Gomina ipinlẹ Ogun, Ọmọọba Dapọ Abiọdun, buwọ lu u pe…