Gbogbo agbara ni mo sa lati jẹ ki igbeyawo yii tọjọ-Olori Ṣilẹkunọla

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Olori Naomi Silẹkunọla to jẹ Olori laafin Adimula telẹ, ṣugbọn to ti kede…

Lẹyin igbeyawo ọdun mẹta, Olori Ṣilẹkunọla kọ Ọọni Ileefẹ silẹ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Olori Ọọni Ifẹ, Ẹfanjẹlisti Naomi Ṣilẹkunọla Ogunwusi, ti kede pe oun ki i…

Alaafin gbẹsẹ le ade Ọba Ẹdu l’Ọyọọ, lo ba lọọ kan an mọgi laafin rẹ

Ọlawale Ajao, Ibadan Owe Yoruba to sọ pé “Ade ori la fi i m’ọba, ilẹkẹ ọrun…

  Lati Ibadan lawọn eleyii ti lọọ jale n’llọrin tọwọ fi tẹ wọn

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ileeṣẹ ọlọpaa ẹka ti ipinlẹ Kwara ti mu awọn afurasi adigunjale mẹta yii,…

Makinde fun ileegbimọ aṣofin lominira lati da duro

Ọlawale Ajao, Ibadan Gomina ipinlẹ Ọyọ, Ẹnjinnia Ṣeyi Makinde, ti ro ileegbimọ aṣofin ipinlẹ naa lagbara…

Diẹ lo ku ki n para mi nigba kan, orin l’Ọlọrun fi doola ẹmi mi – Ọọni

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọọni Ifẹ, Ọba Adeyẹye Ẹnitan Ogunwusi, Ọjaja Keji, ti ṣapejuwe orin gẹgẹ bii…

  Nitori pe o sọrọ si gomina lori Fesibuuku, ijọba ni  ki olukọ kan lọọ rọọkun nile l’Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Olukọ kan to n ṣiṣẹ nileewe Maṣifa Community Grammar School, Maṣifa-Ile, nipinlẹ Ọṣun,…

Awọn agbebon ji Aafaa Jẹlili atọrẹ ẹ gbe l’Ayetoro, ni wọn ba n beere miliọnu mẹẹẹdogun leyin ti wọn pari ọbẹ tiyawo ẹ sẹsẹ se

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta  Ifọkanbalẹ lawọn ajinigbe marun-un kan fi ji Aafaa Abduljẹlii ati ikeji ẹ, Aafaa…

Eko lawọn meji yii ti digun gba mọto, ipinlẹ Ogun ni wọn ti mu wọn

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Loruganjọ ogunjọ, oṣu kejila yii, lawọn ọkunrin meji yii, Kenneth Akpa ati Adebayọ…

Aadọta Naira ni Michael fi tan ọmọ onipọfupọọfu to fipa ba lo pọ n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Akolo ajọ ẹsọ alaabo, ṣifu difẹnsi, ẹka ti ipinlẹ Kwara, ni ọkunrin ẹni…

Colorado lawọn ọmọ Yahoo fun Uzoma mu l’Abẹokuta to fi ku, ni wọn ba ju oku ẹ nu

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọmọ ti ku iya o gbọ nile. Iyẹn lọrọ ọmọkunrin ẹni ogun ọdun…