Faith Adebọla Ọpọ awuyewuye lo n lọ lori ipo ti gbajugbaja oṣere tiata ilẹ wa, Abilekọ…
Category: Ìròyìn
Ijọba Eko lawọn akẹkọọ ati ileewe Dowen ko mọ ohunkohun nipa iku Sylvester
Jọkẹ Amọri Ijọba ipinlẹ Eko ti ni ileewe Dowen College, to wa ni Ikoyi, atawọn akẹkọọ…
Mọsalasi ati ṣọọṣi ni wọn ti n dawo jọ bayii lati doola awọn mẹreerin ti wọn ji gbe lọna Omu-Aran
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Awọn ajinigbe to ji awọn arinrin-ajo mẹrin: Sunday Balogun, iyawo rẹ, Iya Mary,…
Awọn afọbajẹ yan Lekan Balogun gẹgẹ bii Olubadan tuntun
Ọlawale Ajao, Ibadan Nibi ipade ti awọn eeyan yii, pẹlu apapọ igbimọ Olubadan ṣe ni Gbọngan…
Awọn adigunjale kọ lu Kẹmi Afọlabi, wọn gba nnkan ini ẹ, wọn tun ṣa a ladaa
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Pẹlu bo ṣe jẹ pe alaafia ko fi bẹẹ to fun Kẹmi Afọlabi…
Fungba akọkọ, ijọba fun awọn oṣiṣẹ to fakọ yọ lẹbun ọkọ ayọkẹlẹ l’Ọṣun
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ṣe ni olukọ kan lati ileewe L.A Primary School, Adogbe, nijọba ibilẹ Ariwa…
Nitori ireke aadọta Naira, Hausa gun Yoruba lọbẹ n’llọrin
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ṣe ni ibẹrubojo gbilẹ lọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọṣẹ yii, ni ọja kan to…
Ẹlẹwọn mẹrin padanu ẹmi wọn lasiko ti wọn fẹẹ sa kuro lọgba ẹwọn n’Ileefẹ
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ẹlẹwọn mẹrin niroyin fidi rẹ mulẹ pe wọn padanu ẹmi wọn ni ọgba…
Ọwọ ọlọpaa tẹ Sikiru pẹlu ẹya ara eeyan n’Ikorodu, o loun feẹ fi ṣoogun owo ni
Jọkẹ Amọri Ilu Ikorodu ni awọn ọlọpaa ipinlẹ Eko ti mu ọmọkunrin kan ti wọn porukọ…
Ariyanjiyan bẹ silẹ laarin ọmọọṣẹ Ajimọbi ati agbẹjọro lori ẹni ti yoo jẹ Olubadan tuntun
Ọlawale Ajao, Ibadan Lẹyin ti Olubadan ilẹ Ibadan, Ọba Saliu Akanmu Adetunji, ti waja lọjọ Aiku,…
Ọmọ ọdun mẹrinla to ji ọmọ ọga ẹ gbe l’Ekoo bọ sọwọ ọlọpaa l’Ogun
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọmọ ọdọ ni wọn gba a fun, iyẹn Favour Iwuozor, ọmọdebinrin ọmọ ọdun…