Yahaya Bello fọwọ sọya: Emi ni Buhari maa gbejọba fun lọdun 2023

Faith Adebọla “Lagbara Ọlọrun, lẹyin ti wọn ba ti bura fun mi wọle sipo Aarẹ ati…

Ibo 2023: Awọn to lorukọ ninu ẹgbẹ APC yoo pada si PDP laipẹ-Saraki

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Olori ileegbimọ aṣofin agba tẹlẹ, Dokita Bukọla Saraki, ti sọ pe apẹẹrẹ ti…

Awọn ajinigbe ti tu eeyan marun-un ti wọn ji l’Ekiti silẹ

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọsẹ yii, nileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ekiti kede pe awọn ajinigbe…

Igbimọ tijọba gbe kalẹ lori awọn ọmọ-kewu ti wọn fiya jẹ ni Kwara ni ọna ti wọn gba lu wọn ko daa

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Awọn igbimọ ẹlẹni mọkanla ti Gomina ipinlẹ Kwara, Abdulrahman Abdulrasaq, gbe kalẹ pe…

Ọfiisi Ahamad Alawiye olorin Islam jona l’Ekoo

Kazeem Aderounmu Guruguru ni ọfiisi gbajumọ olorin ẹsin Islam nni, Alhaji Ahamdu Alawiye, to wa ni…

Emi ni mo ran awọn ajinigbe pe ki wọn pa ọmọ aburo baba mi nitori gbese ti mo jẹ ẹ– Haliu

Faith Adebọla Yoruba bọ, wọn ni ẹni ti ọrẹ da ko ma binu, ẹni abinibi n…

Sade yii ma daju o, bileedi lo fi ya ọmọ araale ẹ, o lo ji oun ni ẹgbẹrun mẹta Naira

Faith Adebọla  Ahamọ awọn ọlọpaa tọ n gbọ ẹsun iwa ọdaran abẹle ni ẹka ti wọn…

Jonathan n rin ni bebe ẹwọn o, ọmọ ọdun mẹẹẹdogun lo fipa ṣe ‘kinni’ fun ni Badagry

Jọkẹ Amọri Ọjọ Aje, Mọnde, ọsẹ yii, ni wọn taari ọkunrin ẹni ọdun mẹtadinlọgbọn kan, Jonathan…

Ijọba apapọ ṣe ifilọlẹ owo Naira ori ẹrọ ayelujara (eNaira)

Jọkẹ Amọri Ni Mọnde, ọjọ Aje, ọsẹ yii, ni Aarẹ ilẹ wa, Muhammadu Buhari, ṣe ifilọlẹ…

Nitori wọn ni ko lọọ ra eelo ti wọn yoo fi gbẹbi fun’yawo rẹ wa, ṣọja lu nọọsi meji lalubami n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ileeṣẹ ọmọ ologun to wa ni bareke Sobi, niluu Ilọrin, nipinlẹ Kwara, ti…

Aṣọ ṣọja lawọn eleyii ko sọrun, bẹẹ ogbologbo adigunjale ni wọn

Faith Adebọla Akolo awọn ọlọpaa lawọn ọkunrin meji yii wa lasiko yii, Ọgbẹni Yahaya Armayau, ẹni…