Irọ ni, ijọba ko fọwọ yẹpẹrẹ mu awọn janduku, ohun to yẹ ka ṣe la n ṣe-Lai Muhammed

Adefunkẹ Adebiyi Nitori bi ẹnu ṣe n kun ijọba apapọ Naijiria lori awọn jandunku to n…

Ẹnikẹni to ba fọwọ sofin ‘ma fẹran jẹko’, a o ni ti i lẹyin ninu ibo aarẹ lọdun 2023- Miyetti Allah

Adefunkẹ Adebiyi Oro to o da mi ni mo da ọ lawọn ẹgbẹ Fulani darandaran ti…

Awọn ajinigbe ji eeyan mẹrin gbe n’Ilasa-Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Lẹyin ọsẹ meji ti wọn ji tọkọ-tiyawo kan gbe ni Ilasa-Ekiti, awọn ajinigbe…

Wọn ni ara Sunday Igboho ko ya ni Bẹnnẹ o

 Adefunkẹ Adebiyi Ẹbẹ kan lawọn eeyan Oloye Sunday Adeyẹmọ ( Igboho Ooṣa) n bẹ Aarẹ ilẹ…

Ẹgbẹ PDP yoo jawe olubori nibi eto idibo to n bọ ni Kwara – Bukọla Saraki

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọṣẹ yii, ni Gomina ipinlẹ Kwara tẹlẹ, totun jẹ adari…

Dapọ Abiọdun fun awọn olukọ to fakọ yọ lẹbun ile ati owo nla nipinlẹ Ogun

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Lati mu inu awọn olukọ dun nipinlẹ Ogun, ki wọn si tun le…

Ẹ ṣọra fun jijẹ tọki ati ṣinkin ti wọn ko sinu yinyin wa lati ilẹ okeere, kẹmika ti wọn n lo ni mọṣuari ni wọn n fi si i- NAFDAC

Adefunkẹ Adebiyi Imọran ti lọ setigbọọ awọn eeyan ti wọn fẹran lati maa fi owo wọn…

Dare ran ole lati gba miliọnu mẹta tileeṣẹ rẹ ni ko lọọ gba wa ni banki l’Abẹokuta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Kokoro to n jẹ igba, idi igba lo wa. Iyẹn ni ti oṣiṣẹ…

Eto-ẹkọ lo gba eyi to pọ ju ninu eto-iṣuna ipinlẹ Ọṣun ọdun to n bọ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Bọjẹẹti to din diẹ ni biliọnu lọna aadoje naira (#129.7b) ni Gomina Adegboyega…

Obinrin yii bẹ ọkọ ẹ lori nitori ẹsun agbere

Adefunkẹ Adebiyi Rachel Tetteh lobinrin to kawọ gbera yii n jẹ, lẹyin to bẹ ọkọ ẹ…

Olubadan rọ ọkan ninu awọn baalẹ rẹ loye

Jọkẹ Amọri Nitori awọn iwa aṣemaṣe ti wọn ni o n ṣe, Olubadan ilẹ Ibadan, Ọba…