Wọn ti le Sajẹnti Philipps to pa Mọsurat danu lẹnu iṣẹ ọlọpaa, yoo tun foju bale-ẹjọ

Faith Adebọla, Eko  Ṣe ẹ ranti iṣẹlẹ ibanujẹ to waye lalẹ ọjọ Abamẹta, Satide, ọjọ kọkanla,…

Eyi ni bi awọn janduku ọlọkada ṣe fibinu fọ ọga ọlọpaa lori l’Ekoo, wọn pa a patapata

 Faith Adebọla, Eko  Ko sẹni ti yoo ri fọto ọga ọlọpaa, CSP Kazeem Sumọnu Abọnde, ti…

‘Awọn EFCC mẹẹẹdọgbọn fo fẹnsi wọle mi laarin oru, wọn lawọn ro pe ọmọ ‘Yahoo’ ni mi’

Faith Adebọla, Eko Ori lo ko obinrin oniroyin kan, Abilekọ Nora Okafor, yọ lọwọ iku ojiji…

Ẹyin ọdọ, ẹ jinna si lilu jibiti lori ẹrọ ayelujara o-Ijọba Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Kọmiṣanna to n ri si idagbasoke awọn ọdọ nipinlẹ Kwara, Arabinrin Harriet Adenike…

Iya oṣere ilẹ wa, Nkechi Blessing, ku nigba to ku ọjọ diẹ ko ṣọjọọbi

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Eeyan n wo oju, Ọlọrun n wo ọkan, lohun to ku tawọn eeyan…

Lẹyin oṣu kan aabọ, awọn oṣiṣẹ kootu ipinlẹ Ogun fagi le iyanṣẹlodi

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Iyanṣẹlodi ti awọn oṣiṣẹ kootu ipinlẹ Ogun bẹrẹ lọjọ kọkanla, oṣu kẹjọ, ọdun…

Ẹ wo bi wọn ṣe mura bii ṣọja, agbebọn to n ṣiṣẹ ajinigbe ni wọn ni Kaduna

Faith Adebọla Iṣẹ ṣọja tootọ leeyan maa kọkọ ro pe awọn mẹtẹẹta tọwọ awọn agbofinro ba…

Ọkada okoolenirinwo (420) la gbẹsẹ le laarin ọsẹ kan l’Ekoo, a o si ni i sinmi – Jẹjẹloye

Faith Adebọla, Eko Bawọn ọlọkada to n tẹ ofin irinna ilu Eko loju ba lawọn o…

Ademọla ati Hammed dero ẹwọn, ibọn ni wọn ba lọwọ wọn l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko  Latoko iroko lọ s’oko irokoto ni irinajo awọn genge meji yii, Lukman Hammed,…

Ijọba Naijiria n ha dọla fawọn eeyan dudu l’Amẹrika, ki wọn le ṣewọde tako wa lọdọ Ajọ Iṣọkan Agbaye – Banji Akintoye

Faith Adebọla Alaga ẹgbẹ NINAS, iyẹn ẹgbẹ awọn to fẹẹ ya kuro lara Naijiria, Ọjọgbọn Banji…

Ọlọpaa ko lẹtọọ lati beere iwe-ọkọ lọwọ dẹrẹba, ẹ tẹle wọn lọ si teṣan ti wọn ba fẹẹ mu yin – Odumosu

Faith Adebọla, Eko Kọmiṣanna ọlọpaa ipinlẹ Eko, CP Hakeem Odumosu, ti bẹnu atẹ lu ẹsun tawọn…