Ọwọ tẹ ajinigbe meji nibi ti wọn ti fẹẹ gbowo itusilẹ lori ọmọ ọdun meje l’Agbara

 Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ajinigbe lawọn ọkunrin meji yii, orukọ wọn ni Muhammed Abubakar; ẹni ọdun mejilelogoji (42), ati Clinton Niche;…

O ma ṣe o! Oju orun ni Ranti ti ji, lo ba lọọ ko si kanga n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Aiku, Sunnde, ọṣẹ yii, ni Abilekọ Fatima Ranti, ti agboole Kọla, ni…

Dukia to to miliọnu meje naira jona raurau nibi ijamba ina to ṣẹle niluu Iwo

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Dukia to to miliọnu meje naira lo jona ninu ijamba ina to ṣẹlẹ…

Ọlọrun lo sọ fun mi pe ki n fi Dele Mọmọdu jẹ Aarẹ – Oluwoo

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Oluwoo ti ilu Iwo, Ọba Abdulrosheed Adewale Akanbi, ti sọ pe ṣe loun…

Eyi le o, ajinigbe lawọn gende meji kan fẹẹ mu ti wọn fi ku sodo n’llọrin

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Abamẹta, Satide, opin ọsẹ to kọja yii, ni iṣẹlẹ kayeefi kan ṣẹ…

N’Ileṣa, awọn araadugbo dana sun obinrin alarun ọpọlọ to ṣa awọn alajọgbele rẹ meji pa

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Obinrin kan ti wọn sọ pe o ni arun ọpọlọ, Esther Adu, la…

Wọn ji olukọ Fasiti Akungba Akoko gbe loju ọna Akurẹ si Ikẹrẹ-Ekiti

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Olukọ Fasiti Adekunle Ajasin to wa l’Akungba Akoko, Ọgbẹni Mayọwa David Adinlẹwa, lawọn…

Eeyan mẹrin gan mọ’na, ọpọ fara pa, lasiko ajọdun ni ṣọọṣi Kerubu l’Abule-Ẹgba

Faith Adebọla, Eko O kere tan, eeyan mẹrin lo ti pade iku ojiji, ti ọpọlọpọ si…

Nibi ti Bọlanle ti n digunjale n’Ilese-Ijẹbu ni wọn ti mu un

Adefunkẹ Adebiyi,  Abẹokuta Ni nnkan bii aago mejila aabọ oru ojọ kin-in-ni, oṣu kẹwaa yii, ti…

Eto iṣuna ọdun to n bọ yii maa ro awọn araalu lagbara-Ṣeyi Makinde

 Faith Adebọla Iṣẹ ti de’lẹ fawọn aṣofin ipinlẹ Ọyọ lati ṣayẹwo aba eto iṣuna owo tijọba…

Ole lawọn ọlọpaa n fi igi ti wọn n gbe dina lalaalẹ yii ja o – Mista Makaroni

Faith Adebọla, Eko  Gbajugbaja adẹrin-in poṣonu ilẹ wa to tun maa n ja fẹtọọ ọmọniyan, Ọgbẹni…