Lẹyin ọdun mẹẹẹdogun, ọba tuntun jẹ niluu Fiditi

Faith Adebọla Orin ati ijo lo gba ilu Fiditi, nijọba ibilẹ Afijio kan, nipinlẹ Ọyọ, lọjọ…

Igbimọ to n ṣewadii ẹsun awọn ti SARS fiya jẹ pari ijokoo wọn lẹyin ọdun kan

Faith Adebọla, Eko  Lẹyin ọdun kan gbako ti wọn ti n gbọ oriṣiiriṣii ẹsun, ti wọn…

Naijiria wa lara orilẹ-ede to n fun Singapore lounjẹ, to n fun wọn laṣọ, ki nnkan too yiwọ fun wa-Akintọla

Aderounmu Kazeem Gbajugbaja nla nidii iṣẹ ofin, Amofin-Agba Akintọla Adeniyi ti sọ pe bo tilẹ jẹ…

Inu sọọsi ni Bayọ wa to ti n gbadura, lawọn ọmọ ẹgbẹ okunkun pe e jade, wọn si pa a n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ṣe lawọn ọmọ ẹgbẹ okunkun n rẹ ara wọn danu bii ila niluu…

Babalawo dero ẹwọn, jibiti lo lu alaisan kan l’Ado-Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Yoruba bo, wọn ni ọjọ gbogbo ni ti ole, ṣugbọn ọjọ kan ṣoṣo…

Ṣọọbu ni Mariam wa to ti n taja ti ibọn awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun fi lọọ pa a n’Ilọrin

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin K’Ọlọrun ma jẹ ki abiamọ foju sunkun ọmọ. Nibi ija agba awọn ọmọ…

Oṣu mẹfa ni Jamiu yoo lo lẹwọn o, ẹnjin ọili lo ji l’Abẹokuta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Jamiu Shittu, ọmọkunrin ẹni ogun, ọdun ti gbadajọ ẹwọn oṣu mẹfa bayii niluu…

Ọga ọlọpaa Eko sọrẹnda, wọn ni iwọde EndSARS le waye wọọrọwọ

Faith Adebọla, Eko Kọmiṣanna ọlọpaa ipinlẹ Eko, CP Hakeem Odumosu ti ṣalaye pe ẹtọ gbogbo ọmọ…

Ale meji yọ ada sira wọn nitori Kafaaya, ni ọkan ba ku ninu wọn l’Owode-Ẹgbado

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Iku oro lo pa baba ẹni aadọta ọdun (50) kan ti wọn pe…

Ki ẹnikẹni ma ṣe forukọ Sunday Igboho tọrọ owo lori aisan to n ṣe e o-Agbẹjọro

Jọkẹ Amọri Nitori iroyin pe ara rẹ rẹ ko ya, ajijagbara ọmọ Yoruba nni, Oloye Sunday…

Iya Rainbow ṣọjọọbi, o ni ẹbẹ pataki kan loun n bẹ Ọlọrun

Faith Adebọla, Eko Ayẹyẹ ọjọọbi awọn gbajumọ oṣere ki i ṣe tuntun, tilu-tifọn lọpọ maa n…