A o ni i pariwo rara bi wọn ba fi Sunday Igboho silẹ ti yoo fi lọ siluu oyinbo- Lọọya Falọla

 Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta  Latigba ti wọn ti mu Sunday Igboho ti mọle sorilẹ-ede Olominira Bẹnnẹ, koda pẹlu…

Iya buruku lawọn DSS fi n jẹ awọn eeyan Sunday Igboho latimọle, ounjẹ buruku ni wọn n fun wọn jẹ- Lọọya

Faith Adebọla Oriṣiiriṣii iya ajẹkudorogbo ati ipọnju ni wọn lawọn ẹṣọ agbofinro fi n jẹ awọn…

Nitori bi wọn ṣe pa Sọliu, awọn araalu sun mọto kọsitọọmu mẹta l’Ayetoro

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ko din ni mọto awọn kọsitọọmu mẹta tawọn eeyan fibinu danu sun lọjọ…

Nitori ọrọ Hushpuppi, wọn ti jawee gbele-ẹ fun Abba Kyari

Ọga ọlọpaa patapata lorileede yii, Usman Alkali Baba, ti dabaa pe ki wọn jawee gbele-ẹ fun…

Ẹni kan ku, ọpọ fara pa, nibi eto idibo abẹle l’Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ọdọmọkunrin ẹni ọdun mẹtalelogun kan ti wọn pe orukọ re ni Jide ku…

Nitori ẹsun jibiti, adajọ sọ ayederu sọja sẹwọn ọdun kan n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Ẹti, Furaidee, opin ọṣẹ yii, nile-ẹjọ giga kan niluu Ilọrin, nipinlẹ Kwara,…

Aisan Korona kọ lo pa Racheal Oniga o-Awọn mọlẹbi

Ọkan ninu awọn gbajumọ oṣere tiata ilẹ wa to ku lojiji, Racheal Oniga ti sọ pe…

APC yan awọn oloye ẹgbẹ kaakiri wọọdu ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Abamẹta, Satide, opin ọsẹ yii, ni ipade apapọ ẹgbẹ oṣelu APC, ẹka…

EFCC ti tun mu Bukọla Saraki o!

Faith Adebọla Ileeṣẹ to n gbogun ti iwa jibiti ati ṣiṣe owo ilu mọkumọku, EFCC, ti…

Amọtẹkun yinbọn pa Fulani ajinigbe meji l’Ọyọọ, wọn mu mẹta laaye

Ọlawale Ajao, Ibadan Awọn ajinigbe to n ko iku ati ipaya ba awọn ara ipinlẹ Ọyọ…

Abi iru ki tun leyi: Rachael Oniga ti ku o

Ọkan pataki ninu awọn oṣere tiata nilẹ yii, Oloye Rachael Oniga, ti ku o. Aarọ kutu…