Awọn ọlọpaa n wa Lawal, wọn lo fipa ba ọmọ ọdun mẹrinlelogun sun n’Itele

Adefunke Adebiyi Kọmandi ọlọpaa nipinlẹ Ogun ti fi orukọ ọkunrin kan, Adewumi Lawal, sita bayii pe…

Ounjẹ ọdun ni wọn ni ki Bimpe lọọ gbe fun Waheed, lo ba fipa ba a lo pọ n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Lalẹ ọjọ ọdun Ileya to kọja, nigba ti gbogbo Musulumi ti n dupẹ…

Ọwọ tẹ ọkan ninu awọn ajinigbe to n fi mọto gbero ni garaaji Iwo Road, n’Ibadan (Fidio)

Ọlawale Ajao, Ibadan Ori lo ko awọn ero inu ọkọ kan yọ n’Ibadan lonii, ọkọ ero…

Ijọba ti ileewe meji to ṣẹ sofin Korona pa l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Laarin wakati diẹ tawọn ile-ẹkọ di ṣiṣi pada nipinlẹ Ondo, ijọba ti pasẹ…

Adams di alaga ẹgbẹ PDP l’Ondo

Nibi idibo ẹgbẹ oṣelu PDP ipinlẹ Ondo to waye lonii niluu Akurẹ, nipinlẹ Ondo, ni awọn…

O ṣẹlẹ! Igbakeji gomina Kwara atiyawo ẹ ko arun Korona

Stephen Ajagbe, Ilọrin Iroyin to tẹ wa lọwọ lọsan-an oni, ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ni pe Igbakeji…

Ijamba mọto ti paayan mẹta ni Dọpẹmu

Faith Adebọla, Eko Ijamba ọkọ ayọkẹlẹ to ṣẹlẹ ni nnkan bii aago meji ọsan ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ti…

Mọto takiti ni marosẹ-Eko s’Ibadan, ọmọ irinsẹ atawọn meji mi-in ku

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Lọsan-an oni yii ti i ṣe ọjọ Iṣẹgun,Tusidee, ọjọ kẹrin, oṣu kẹjọ yii, eeyan…

Eyitayọ Jẹgẹdẹ ṣabẹwo si Mimiko l’Ondo

Ni nnkan bii aago mẹjọ alẹ ọjọ Aje, Mọnde, ọsẹ yii, ni oludije sipo gomina ninu…

Gomina Kwara gbe igbimọ oluwadii dide lori owo ti wọn lo n poora nijọba ibilẹ

Stephen Ajagbe, Ilọrin Latari iroyin to n kaakiri igboro pe awọn alaṣẹ ijọba kan n yọ…

Bamgboye ku lojiji nitori jibiti miliọnu marun-un ti Peter lu oun atiyawo ẹ l’Abẹokuta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Peter Gbese, ẹni ọdun mẹtadinlogoji (37), ki i ṣe ọmọ Naijiria, ilẹ Olominira…