Oshiomhole jẹwọ: o ni, ọja buruku ni mo ta fẹyin ara Edo ni 2016

Ni gbangba waalia, GRA, ilu Binni ni olori ẹgbẹ APC tẹlẹ, Adams Oshiomhole, ti sọrọ naa…

O ṣẹlẹ: Akpabio ti darukọ awọn aṣofin ti wọn jọ kowo jẹ o

Minisita to n ri si ọrọ agbegbe Niger Delta, Oloye Godswill Akpabio, ti darukọ awọn aṣofin…

O ma ṣe o, kọntena ja bọ le bọọsi akero lori n’Ilasamaja, eeyan meji lo ku lẹsẹkẹsẹ

Faith Adebọla, Eko Iku oro, iku gbigbona, gbaa ni iku to mu ẹmi eeyan meji lọ…

Ijọba ti fi katakata yanju iyooku ile to wo l’Ebute-Mẹtta, wọn ni ki lanlọọdu ile naa yọju kia

Faith Adebọla, Eko Laika ti pe ayẹwo ṣi n lọ lori ohun to fa iṣẹlẹ ile…

Meji to ku ninu awọn Fulani to n jale ni marosẹ Eko s’Ibadan ti bọ sọwọ ọlọpaa

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọwọ ọlọpaa ipinlẹ Ogun ti tẹ  meji yooku ninu awọn ọmọde ole to…

Ẹ woju awọn ọrẹ meji yii, ayederu ọili ni wọn n ṣe, ladajọ ba ju wọn sẹwọn ọdun mẹrin l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko Arikọgbọn ati abamọ nibi tọrọ awọn afurasi ọdaran meji tẹ ẹ n wo…

Ijọba apapọ ṣi papakọ ofurufu mẹrinla

Oluyinka Soyemi Ijọba apapọ ilẹ Naijiria ti fọwọ si ṣiṣi awọn papakọ ofurufu mẹrinla lẹyin awọn…

Awọn ọmọ iya meji ti wọn fẹẹ ṣ’oogun owo n’Ijẹbu ti pa iya arugbo o

Ni Ijẹbu Muṣin lo ti ṣẹlẹ. Awọn ọmọ iya kan naa, Akinọla Akeem ati Muyiwa Akeem…

Awọn Hausa atawọn ọmọọta n ja l’Oṣogbo o

Ija kan teeyan ko ti i gbọ hulẹhulẹ ohun to fa a gan-an bẹ silẹ laarin…

Baba Gomina Kwara, AbdulGaniyu Abdul-Razaq, jade laye lẹni ọdun mẹtalelaaadọrun-un

Stephen Ajagbe, Ilọrin Laaarọ ọjọ Abamẹta, Satidee, yii, ni ẹbi Abdulrazaq kede iku baba Gomina Kwara,…

Arotile: Wọn ti fa awọn afurasi ati mọto wọn le ọlọpaa lọwọ

Ileeṣẹ ọmọ-ogun ofururu Naijiria ti fa awọn mẹta ti wọn fẹsun kan lori iku Tolulọpẹ Arotile…