Koronafairọọsi tun ti gbẹmi eeyan meji l’Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Kọmisanna feto ilera nipinlẹ Ọṣun, Dokita Rafiu Isamọtu, ti kede pe arun koronafairọọsi…

Yahaya Bello jawe olubori nile-ẹjọ ko-tẹ-mi-lọrun

Gomina ipinlẹ Kogi, Yahaya Bello, ti jawe olubori nile-ẹjọ ko-tẹ-mi-lọrun latari ẹjọ tawọn kan pe tako…

Olori ọmọ-ogun ofurufu fi gbedeke le ogun Boko Haram

Olori awọn ọmọ-ogun ofurufu nilẹ yii, Ọgagun Sadique Abubakar, ti ṣeleri pe opin ọdun yii ni…

Ijọba ipinlẹ Ọṣun kede igbele nijọba ibilẹ mẹrin

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Latari bi arun koronafairọọri ṣe n fojoojumọ gbilẹ niluu Ileṣa, Gomina Gboyega Oyetọla…

Gomina Kwara pa ipo awọn kọmiṣanna marun-un da

Stephen Ajagbe, Ilọrin Lọjọ Ẹti, Furaidee, ọsẹ yii, ni Gomina ipinlẹ Kwara, Abdulrahman Abdulrazaq, pa ipo awọn kọmiṣanna rẹ kan…

Ọshinọwọ ti dero ẹwọn o, owo ijọba lo ko jẹ l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko Ibanujẹ ti wọn lo n dori agba kodo lọrọ da fun Ọgbẹni Stephen…

Adesọji Aderẹmi ni arole mi yoo maa jẹ – Ọọni Ogunwusi

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Fun ipa rere ati orukọ manigbagbe ti Sir Adesọji Tadenikawo Aderẹmi, ẹni to jẹ…

Gomina Ebonyi lugbadi koronafairọọsi, aṣẹ bọ sọwọ igbakeji

Gomina ipinlẹ Ebonyi, Dave Umahi, ti lugbadi arun koronafairọọsi pẹlu awọn amugbalẹgbẹ rẹ kan. Umahi lo…

Miliọnu mẹta eeyan forukọ silẹ fun N-Power

Ijọba apapọ ti kede pe awọn to le ni miliọnu mẹta lo ti forukọ silẹ fun…

Awọn ileewe Eko yoo ṣi loṣu to n bọ

Ijọba ipinlẹ Eko ti kede pe awọn ileewe ipinlẹ naa yoo ṣi lọjọ kẹta, oṣu to…

Ijọba ṣeleri lati ṣatunṣe ọna Kaiama si Baruten

Stephen Ajagbe, Ilọrin Abẹnugan ile igbimọ aṣofin ipinlẹ Kwara, Ọnarebu Yakubu Danladi-Salihu, ti fi da awọn…