Faith Adebọla Bi ọkunrin ẹni ọdun mejilelọgbọn kan, Aboh Ogbeche, ṣe jokoo siwaju mama ẹ ni…
Category: Ìròyìn
Ekiti, Ogun atawọn ipinlẹ meji mi-in ni kọmiṣanna ọlọpaa tuntun
Oluyinka Soyemi Awọn kọmiṣanna tuntun ti bẹrẹ iṣẹ nipinlẹ Ekiti, Ogun, Cross River ati Bayelsa lẹsẹkẹsẹ.…
Laaarọ yii, Buhari pade Jonathan ninu Aso Rock
Olori ijọba Naijiria, Aarẹ Muhammadu Buhari, ṣe akanṣe ipade kan loni-in yii pẹlu aarẹ ilẹ wa…
Ija n bọ: Awọn aṣofin ti ni kawọn olori ologun gbogbo fipo silẹ o
Ile-gbimọ aṣofin agba ilẹ yii ti paṣẹ loni-in yii pe ki awọn olori ologun gbogbo fi…
A maa ṣamulo ọgbọn ibilẹ ati tigbalode fun iṣẹ Amọtẹkun – Kọmọlafẹ
Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Adari ikọ Amọtẹkun nipinlẹ Ekiti, Ọgagun-fẹyinti Joe Kọmọlafẹ, ti sọ pe ọgbọn ibilẹ…
Awọn ololufẹ Samuel Kalu to ko Korona wọle adura fun un
Oluyinka Soyemi Awọn ololufẹ agbabọọlu ilẹ Naijiria to n ṣe bẹbẹ ni Bordeaux, ilẹ France, Samuel…
Awọn aṣofin beere boya o kowo jẹ ni o, n lọga ileeṣẹ NDDC ba daku
Ọrọ buruku ni, koda o mu ẹrin lọwọ, ṣugbọn awọn ti wọn wa nibẹ ko…
Ṣe ẹyin naa ti ra ALAROYE ọsẹ yii? Ẹ gbọ awọn iroyin to wa nibẹ…
Ṣe ẹyin naa ti ra ALAROYE ọsẹ yii? Ẹ tete beere tiyin lọẉọ fẹndọ ko too…
Korona mu oṣiṣẹ DSTV n’Ibadan, wọn ba ni kawọn onibaara wọn lọọ fira wọn pamọ sile
Ọlawale Ajao, Ibadan Oṣiṣẹ ileeṣẹ Multichoice, iyẹn ileeṣẹ to ni ẹrọ amohunmaworan alatagba ti wọn n…
IBO APC: AKEREDOLU LO WỌLE
Ibo abẹle APC ti wọn di lanaa ni ipinlẹ Ondo, Gomina Rotimi Akeredolu lo ma wọle. …
ISSA FUNTUA, ỌKAN NINU AWỌN IGI-LẸYIN-ỌGBA BUHARI, TI KU O
NInu ile ijọba Aso Rock, a-gbọ-sọgba-nu ni iroyin iku ọhun jẹ. Awọn eeyan ibẹ ko tete…