Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ṣe lawọn alaṣẹ liigi ilẹ Zambia to yẹ ko bẹrẹ lọjọ Abamẹta, Satide,…
Category: Ìròyìn
‘A FẸẸ MỌ IKU TO PA ỌMỌ WA O,’ AWỌN YORUBA KOGI BINU
Ọrọ iku to pa ọmọọbinrin afẹronpileeni-jagun, Tolulọpẹ Arotile, ko ti i tan nilẹ rara, nitori iruju…
Oṣiṣẹ wa to ba gbowo ẹyin atẹni to fun un yoo foju bale-ẹjọ-FRSC
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ajọ ẹṣọ alaabo oju popo (FRSC), ti kede pe eyikeyii ninu awọn oṣiṣẹ…
KO SAAYE ỌDUN IBILẸ KANKAN NI GBOGBO EKITI BAYII O
Gbogbo ọdun ibilẹ pata ni wọn ti fi ofin de ni ipinlẹ Ekiti bayii o. Bo…
“Ẹ MA JẸ KAWỌN ỌMỌLEEWE WỌLE O, Ẹ JẸ KO D’ỌDUN TO N BỌ”
Ẹgbẹ awon olukọ ni yunifasiti gbogbo nilẹ yii ti wọn n pe ni ASUU ti sọ…
Aṣiṣe nla ni bi mo ṣe fi Agbọọla ṣe igbakeji mi – Akeredolu
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ. Asiṣe nla gbaa lo jẹ fun mi lori bi mo ṣe yan Agboọla…
Kọmiṣanna eto ẹkọ ti ko si nipinlẹ Ogun n fa wa sẹyin-Ẹgbẹ Akẹkọọ
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Apapọ ẹgbẹ akẹkọọ nipinlẹ Ogun, ‘National Association of Ogun State Students’ (NAOSS), ti fi…
Korona: Ijọba ko aadọta eeyan nile-ijo taka-sufee n’Ilọrin
Stephen Ajagbe, Ilorin Fun pe wọn tapa sofin to de ṣiṣi ile-ijo lasiko ajakalẹ arun Korona,…
Haa, awọn ajinigbe ti gbe’yawo atọmọ olori ile-igbimọ aṣofin ipinlẹ Edo tẹlẹ lọ o
Ajalu ti di meji fun wọn ni ipinle Edo bayii o. Wọn ti ji iyawo ati…
Lẹyin ti Ojo atawọn ọrẹ ẹ fipa ba ọmọ lo pọ tan ni wọn tun fẹẹ ki iya mọlẹ n’Ikarẹ-Akoko
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ. Awọn afurasi mẹrin ti wọn fẹsun ifipabanilopọ kan ni wọn ti…
Ojoojumọ lọkọ mi maa n lu mi nilukilu nitori ibalopọ, mi o fẹ ẹ mọ – Esther
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Kootu kọkọ-kọkọ to wa lagbegbe Oke-Ẹda, l’Akurẹ, ni obinrin ẹni ọdun marundinlogoji kan, Esther…