Awọn oṣiṣẹ ijọba Ekiti fẹẹ ba Fayẹmi k’ẹsẹ bọ ṣokoto ija o

Gbogbo ẹgbẹ awọn oṣịṣẹ patapata ti para pọ ni ipinlẹ Ekiti bayii o, wọn si ni…

O ga o: terela Dangote tun g’ori ọlọkada l’Agọ-Iwoye, o pa a patapata

Laaarọ yii ni. Ere buruku ni wọn ni mọto terela Dangote naa n ba bọ, o…

O ṣẹlẹ! Akeredolu sọrẹnda

  Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ   Lẹyin bii ọdun mẹta o le to ti gori aleefa, Gomina…

‘Nitori owo ni mo ṣe bẹ ọrẹ mi lori o!’, Moses lo sọ bẹẹ

Afi ki eeyan maa ṣọra ko too finu han fẹni kan. Awọn ọrẹ a maa ṣeku…

O MA ṢE O: AWỌN ỌLỌPAA MẸTA KU S’OD0 NILUU ỌYỌ

Awọn ọlọpaa mẹta kan ti ba omi lọ nilu Ọyọ Alaafin o. Wọn ko somi, wọn…

Ẹ woju wọn, awọn ni wọn pa Barakat, ti wọn tun pa alaboyun atawọn mi-in l’Akinyẹle, n’Ibadan

  Titi di ba a ṣe n sọ yii ni gbogbo awọn to wa nibi tawọn…

Ipade alaafia awọn oludije sipo gomina ẹgbẹ APC Ondo fori sanpọn

  Iyiade Oluṣẹyẹ, Akurẹ Afaimọ ki fa-a-ka-ja-a to n fojoojumọ ṣẹlẹ ninu ẹgbẹ oṣelu APC nipinlẹ…

Nitori bi korona ṣe pa ọkan ninu wọn, awọn aṣofin Eko bẹrẹ ayẹwo

  Latari aṣẹ tileegbimọ aṣofin Eko  pa pa pe ki gbogbo awọn ọmọ ile aṣofin naa,…

N’ILE-IFẸ, WỌN NI JUBIRILA J’IYAWO ONIYAWO GBE TỌMỌTỌMỌ

Wọn ti wọ ọkunrin kan to n jẹ Jubril Anifowoṣe lọ sile-ẹjọ ni Ile-Ifẹ o. Lanaa…

Ẹgbọn Tolulọpẹ ti sọrọ o, o ni iku aburo oun ki i ṣoju lasan

Oriṣiiriṣii awuyewuye lo ti n lọ lori iku to pa ọdọmọbinrin kan, Tolulọpẹ Arotile, ẹni to…

Wọn ti yan Yaya Bello gẹgẹ bii alaga igbimọ ti yoo ṣeto idibo abẹle APC nipinlẹ Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ  Gomina ipinlẹ Kogi, Alaaji Yaya Bello, ni wọn ti kede orukọ rẹ gẹgẹ…