Nigba ti alaga igbimọ awọn gomina ẹgbẹ APC, Atiku Bagudu to tun jẹ gomina ipinlẹ Kebbi…
Category: Ìròyìn
Olori oṣiṣẹ Gomina Zulum tipinlẹ Borno jade laye
Olori oṣiṣẹ Gomina Babagana Zulum tipinlẹ Borno, Babagana Wakil, ti jade laye. Wakil lo jẹ Ọlọrun…
Ijọba apapọ fi kun owo-epo bẹntiroolu
Ijọba apapọ ilẹ Naijiria ti fi kun owo epo bẹntiroolu, eyi to gbera kuro ni naira…
Awọn ẹruuku tun ya wọ Akinyẹle, n’Ibadan, wọn ṣa iya atọmọ ladaa
Ọlawale Ajao, Ibadan Pẹlu bi awọn ẹni ibi kan ṣe n pa awọn eyan nipakupa lagbegbe Akinyẹle, n’Ibadan, awọn…
Ọwọ tẹ Tọpẹ nibi to ti n fọle onile l’Ondo
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Diẹ lo ku ki wọn dana sun afurasi adigunjale kan, Tọpẹ Owolabi, tọwọ…
Micheal ti wọn sọ pe o payawo atọmọ ẹ n’Ileefẹ ti foju bale-ẹjọ
Michael Adunọla ti fara han niwaju ile-ẹjọ Majisreeti ilu Ileefẹ lori ẹsun pe o pa iyawo…
Ile-ẹjọ sọ awọn ọmọ orileede India meji to n ji epo rọbi satimọle
Faith Adebọla, Eko Afaimọ kawọn ọmọ ilẹ India meji yii, Akash Kumar ati Vishal Guleria ma…
IDAAMU OLUWOO: Ọba to ti ṣẹwọn l’Amẹrika nigba kan
Loootọ ni Ọba naa ti n jagun tipẹ, bo tilẹ jẹ pe ọpọ ogun naa jẹ…
Sunday ọlọkada gbe ọmọ ẹgbẹ okunkun pẹlu ibọn n’Ijẹbu-Ode, ni wọn ba ko sọwọ ọlọpaa
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Bo tilẹ jẹ pe Sunday Francis, ọlọkada ẹni ọdun mejidinlogoji (38) n’Ijẹbu-Ode, sọ…
Oogun oloro: Ajọ NDLEA ṣekilọ fawọn ọdaran lẹyin tọwọ tẹ mọkandinlaaadọfa
Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Adari ajọ to n gbogun ti oogun oloro nilẹ yii (NDLEA), ẹka tipinlẹ…
Olusin tilu Isanlu-Isin rọ oloye kan loye, niyẹn ba ni awada lasan ni
Stephen Ajagbe, Ilorin Nitori iwa ijọra ẹni loju, jagidijagan ati dida ilu ru, Olusin tilu Isanlu-Isin,…