Olu-Theo Omolohun, Oke-Ogun Ṣe ọjọ gbogbo ni tole, ọjọ kan ni to toloun, aṣiri baba ọkọ…
Category: set feature image
Ijọba kede Ọjọruu ati Ọjọbọ gẹgẹ bii isinmi ọdun Itunu aawẹ
Ijọba apapọ ti kede Ọjọbọ, Wẹsidee, ọjọ kejila, ati Tọsidee, ọjọ kẹtala, oṣu yii, gẹgẹ bii…
Tori Korona, ijọba apapọ tun da ofin konilegbele pada
Faith Adebọla Pẹlu bi arun Koronafairọọsi tun ṣe n lagbara si i lawọn orileede agbaye kan…
Pelu bi eto ọrọ-aje ṣe denukọlẹ, ijọba mi ko ni i gbaṣẹ lọwọ oṣiṣẹ kankan- Akeredolu
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Lasiko to n sinu aawẹ pẹlu awọn Musulumi lalẹ ọjọ Aiku, Sannde ọsẹ…
O ma ṣe o, ọkọ akoyọyọ tẹ ọlọkada meji pa l’Akurẹ
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Awọn meji ni wọn pade iku ojiji lọjọ Aiku, Sannde ọsẹ yii, pẹlu…
Amotẹkun ti mu awọn Fulani to fipa ba awọn obinrin ti wọn ji gbe lo pọ l’Akurẹ
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Awọn ajinigbe mẹrin kan lọwọ ẹsọ Amọtẹkun ipinlẹ Ondo tẹ niluu Akurẹ lọjọ…
Ole meji ku soju ija ni Ṣagamu, awọn ọlọpaa lo yinbọn fun wọn
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Lọjọ Aiku, Sannde, ọsẹ yii, lawọn ole meji kan ku ni lairo tẹlẹ.…
Naijiria o le wa niṣọkan labẹ ijọba Buhari yii – Wọle Ṣoyinka
Faith Adebọla, Eko Ogbontarigi onkọwe to dantọ ni, Ọjọgbọn Wọle Ṣoyinka, ti sọ pe ko si…
Awọn ọba Amosun yari fun igbimọ Oloye Kemta, wọn lawọn o ki i ṣe baalẹ, Tẹjuoṣo naa loun ṣi ni Olu Orile-Kemta
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Latari bi igbimọ Oloye Kemta(Kemta Council Of Chiefs) nipinlẹ Ogun, ṣe ni awọn…
Mi o bu Pasitọ Adeboye o, awọn alabosi lo n sọsọkusọ kiri – Sunday Igboho
Faith Adebọla Ilu-mọ-ọn-ka ajijagbara ilẹ Yoruba nni, Sunday Adeyẹmi, ti inagijẹ rẹ n jẹ Sunday Igboho…
Aṣegbe o si fẹnikẹni to ba pa Fulani, tọhun maa san gbese ẹ dandan ni – Gomina El-Rufai
Faith Adebọla Gomina ipinlẹ Kaduna, Mallam Nasir El-Rufai, ti sọ pe dandan ni kawọn Fulani gbẹsan…