Awọn Fulani darandaran kọ lu agbẹ meji ninu oko l’Ẹrinle

Stephen Ajagbe, Ilorin Awọn agbẹ meji; Joseph Goje ati Nathaniel Goje, ti wọn fi ilu Ọyan,…

Sunday Igboho yari: A maa bẹrẹ si i wọgbo lọọ ba awọn Fulani kaakiri ilẹ Yoruba

Faith Adebọla Gbajugbaja ajijagbara ilẹ Yoruba nni, Sunday Adeyẹmọ, ti gbogbo eeyan mọ si Sunday Igboho,…

Wọn ti ju wolii to wọn lọfinda sara Kayọde tina fi jo o pa ni ṣọọṣi Sẹlẹ satimọle

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Lẹyin iku ojiji to pa ọkunrin kan, Kayọde Badru, to ṣẹṣẹ ti Dubai…

Awọn alailaaanu ọmọ Naijiria kan lo fẹẹ doju ijọba mi de

Faith Adebọla Aarẹ orileede yii, Ajagun-fẹyinti Muhammadu Buhari, ti sọ pe o ṣi n ya oun…

‘Ọro eto aabo to mẹhẹ ki i ṣẹjọ ijọba Buhari’

Faith Adebọla Minisita feto igbokegbodo ọkọ, Rotimi Amaechi, ti gbeja ijọba to wa lode yii lori…

Nitori ominira Yoruba: Wọn nijọba Naijiria ti n kọ lu awọn ẹbi Ọjọgbọn Banji Akintoye

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Ẹgbẹ Ilana Ọmọ Oodua (IOO), iyẹn ọkan ninu awọn ẹgbẹ to n pe fun…

Akwa Ibom lawọn ọmọbinrin keekeeke yii waa ṣiṣẹ aṣẹwo l’Ogun

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ko din ni mejilelogun (22) awọn ọmọdebinrin ti awọn ọlọpaa ipinlẹ Ogun ri…

Awọn akẹkọọ ileewe Kaduna ti wọn ṣẹṣẹ tu silẹ lawọn ko wẹ fun odidi oṣu meji

“Awọn agbebọn wọnyi nilo adura gidi, adura nikan ni ka maa gba ki Ọlọrun fọwọ tọ…

Awọn ajinigbe pa iya agbalagba ti wọn ji gbe ni Benue, Ọṣun ti wọn sa wa lọwọ ti tẹ wọn

Florence Babaṣọla Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Oṣun ti tẹ awọn ajinigbe mẹjọ labule Ọmọ-Ijeṣa. Ọjọ keje,…

Nitori rogbodiyan to waye lawọn ibi kan l’Ondo, afurasi bii ogun ti wa lahaamọ ọlọpaa

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Awọn afurasi janduku bii ogun lọwọ awọn ọlọpaa ti tẹ latari ipa ti…

Kootu ju iyawo to n wo foonu ọkọ ẹ lai gbaṣẹ sẹwọn oṣu mẹta

Fun bo ṣe maa n ji foonu ọkọ ẹ wo lalaalẹ nigba ti ọkunrin naa ba…