Latari rogbodiyan to waye l’Ọwọ, ẹgbẹ OPC kọwe sileeṣẹ ọlọpaa Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ẹgbẹ OPC, ẹka tipinlẹ Ondo, ti fẹhonu han lori bawọn ọmọ ẹgbẹ okunkun…

Ajọ eleto idibo fẹẹ ṣafikun awọn ibudo idibo to wa nipinlẹ Ondo

 Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ajọ eleto idibo lorilẹ-ede yii ti kede ipinnu wọn lati ṣafikun si awọn…

 ‘Mama Taraba,’ minisita fọrọ awọn obinrin tẹlẹ ti ku o

Faith Adebọla Ṣe ẹ ranti gbajugbaja oloṣelu obinrin ọmọ bibi ipinlẹ Taraba nni,  Aisha Jummai Alhassan,…

Gomina Benue ti fawọn fijilante ipinlẹ rẹ laṣẹ lati maa gbebọn kiri

Faith Adebọla Gomina ipinlẹ Benue, Samuel Ortom, ti kede pe oun iyatọ patapata maa wa ninu…

Nitori irẹsi ilẹ okeere: Onifayawọ meji ku, aṣọbode ati ṣọja fara gbọta l’Ọja-Ọdan

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Eeyan meji ti wọn jẹ onifayawọ ni wọn pade iku ojiji l’Ọjọbọ, ọjọ kẹfa,…

Awọn alaga kansu ti Makinde le danu fẹyin ẹ janlẹ ni kootu, adajọ ni ko sanwo itanran

Ọlawale Ajao, Ibadan Awọn alaga kansu ti ilu dibo yan kaakiri ijọba ibilẹ mẹtẹẹtalelọgbọn (33) ni…

Tusidee to n bọ ni wọn yoo sinku ọmọ Baba Adeboye

Bi gbogbo nnkan ba lọ bi wọn ṣe ṣeto rẹ, ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọsẹ to n…

Mọto gbokiti ni marosẹ Eko s’Ibadan, ni ina ba jo awọn ero ọkọ pa

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Lasiko ti a n kọ iroyin yii, ko ti i sẹni to mọ…

Wike kọ lu Buhari, o nijọba ẹ ko bikita bi oku eeyan ba kun gbogbo opopona

Faith Adebọla Gomina ipinlẹ Rivers, Amofin Nyesom Wike, ti sokọ ọrọ si ijọba apapọ ti Aarẹ…

Ko si ọba alaye to gbọdọ fun ajoji kankan laaye lati tẹdo si agbegbe wọn l’Ondo-Akeredolu

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Gomina Rotimi Akeredolu ti ni ko si ọba alaye ipinlẹ Ondo to gbọdọ…

Awọn nọọsi yari mọ Akeredolu lọwọ l’Ondo, wọn lawọn ko gba aabọ owo-oṣu to fẹẹ san

Ẹgbẹ awọn nọọsi ẹka tipinlẹ Ondo ti kọ jalẹ lati gba aabọ owo-osu keji, ọdun yii,…