Awọn agbebọn kọ lu teṣan ọlọpaa l’Akurẹ, wọn pa ọlọpaa kan

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Lasiko tawọn janduku lọọ kọ lu teṣan ọlọpaa Ẹlẹrinla, eyi to wa lagbegbe…

Nitori to ji apo saka-saka ko, adajọ sọ Ayuba sẹwọn ọdun mẹta ni Kwara

Ibrahim Alagunmu Ile-ẹjọ Magistreeti kan niluu Kaiama, nipinlẹ Kwara, ti sọ Arakunrin ẹni ọdun mejilelogun kan,…

Ọlọpaa bẹrẹ iwadii lori ọmọ ọba Ọfatẹdo tawọn ọmọ ẹgbẹ okunkun yinbọn pa l’Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Inu ọfọ nla ni awọn mọlẹbi Ọlọfa ti ilu Ọfatẹdo, nijọba ibilẹ Ẹgbẹdọrẹ,…

Lẹyin ti Biọla gba ipe tan lori foonu lawọn agbebọn yinbọn pa a n’llọrin

Ibrahim Alagunmu Onisowo pataki kan, Biọla Osundiyan, ni awọn agbebọn ti yinbọn pa nibi to ti…

Lati le gba kaadi idibo, ijọba Ogun kede ọjọ Iṣẹgun bii isinmi lẹnu iṣẹ

Gbenga Amos, Ogun  Agan lọrọ eto idibo gbogbogboo to n bọ lọna dẹdẹ lọdun 2023, afi…

Ija Mọla ati Yoruba ni Sanni n la, lawọn Hausa ba lu u pa n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Awọn agba bọ, wọn ni onlaja ni i fara gbọgbẹ. Ṣugbọn ọrọ buru…

Ijọba yoo bẹrẹ si i gbowo too-geeti pada ti ọna Eko s’Ibadan ba ti pari – Faṣọla

Faith Adebọla, Eko Iroyin ayọ lo jẹ nigba ti Minisita fun iṣẹ ode nilẹ wa, Amofin…

Ẹ jẹ ka fi ọrọ ẹsin sẹgbẹẹ kan, APC lawọn eeyan ṣi maa dibo fun lọdun 2023 – Faṣọla

Faith Adebọla Lai ka bi awuyewuye ṣe gbode kan lori iyansipo aarẹ ati igbakeji rẹ ti…

Wọn ka Kẹhinde mọ’bi to ti n bu majele sounjẹ ọga rẹ l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko ti foju awọn afurasi ọdaran meji kan, Kẹhinde Aroyi,…

Ọwọ ọlọpaa tẹ ọmọ ẹgbẹ okunkun meje ni Omuo-Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ẹka to n gbogun ti ẹgbẹ okunkun ti ajọ ọlọpaa ipinlẹ Ekiti ti…

Erin wo! Asẹyin ilu Isẹyin waja

Ọlawale Ajao, Ibadan Asẹyin tilu Iṣẹyin, Ọba Abdul Ganiy Adekunle Salawudeen (Ajinẹsẹ Keji), ti waja. Iroyin…