Ọmuti dẹrẹba fi mọto pa ọmọ iya mẹta lẹẹkan naa

Adewale Adeoye Ọsẹ yii gan-an ni ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Nasarawa lawọn maa foju Ọgbẹni Ya Zakari, dẹrẹba mọto ayọkẹlẹ kan to…

Kayeefi! Iyaale ile yii ji ara rẹ gbe, lo ba ni kileeṣẹ oun waa sanwo itusilẹ

Adewale Adeoye Ọdọ awọn ọlọpaa agbegbe Edo, nipinlẹ Edo, ni iyaale ile kan, Abilekọ Blessing Ogunu, atawọn ọrẹ rẹ meji kan, Abilekọ Esther Anthony ati Ogbẹni Ukpebor Joel wa, wọn…

Aṣa palapala, inu mọto ni akẹkọọ ati tiṣa yii ti ṣe ‘kinni’ funra wọn

Adewale Adeoye Awọn ọlọpaa Nebraska, lorileede Amẹrika, ti mu Abilekọ Erin Ward, ẹni ọdun marundinlaaadọta, to jẹ olukọ nileewe girama kan lagbegbe…

Nibi ti wọn paaki tirela to kun fun ororo si ni ọkunrin yii ti ji i gbe lọ

Adewale Adeoye Ọdọ awọn ọlọpaa ipinlẹ Bauchi, ni ọgbẹni kan tawọn ọlọpaa lawọn ko fẹẹ darukọ rẹ sita nitori ti iwadii ṣi n lọ lọwọ nipa rẹ wa…

Awọn ọrẹ meji yii rawọ ẹbẹ sijọba: A ti ronupiwada, a ko ṣẹ Boko Haram mọ, ẹ dariji wa

Adewale Adeoye Meji lara awọn ojulowo ọmọ ẹgbẹ Boko Haram to n doju ija kọ awọn araalu nigba gbogbo…

O ma ṣe o, mọto ṣọja pa oni-Kẹkẹ Marwa ati ero meji to gbe

Adewale Adeoye Ṣe lọrọ ọhun di bo o lọ o yago fun mi lọjọ Aiku, Sannde, ọjọ kẹrinla, oṣu Kẹrin, ọdun 2024 yii, nigba ti mọto awọn ṣọja…

Awọn ọmọ Naijiria yii ti gungi re kọja ewe o, egboogi oloro ni wọn n ta ni Thailand

Adewale Adeoye Ọwọ awọn ọlọpaa to n gbogun ti gbigbe ati lilo egboogi oloro lorileede Thailand ti tẹ awọn…

Ija ọmọ ẹgbẹ okunkun bẹ silẹ l’Ajegunlẹ, ẹni kan ku, ọpọ fara pa yannayanna

Adewale Adeoye Ọmọ ẹgbẹ okunkun kan to jẹ ẹni ọdun mẹẹẹdọgbọn tawọn ọlọpaa agbegbe Ajegunlẹ, nipinlẹ Eko, ko fẹẹ darukọ nitori ti iwadi ṣi n…

Ijamba ọkọ fẹmi eeyan meji ṣofo, mẹtala fara pa yannayanna

Adewale Adeoye Eeyan meji lara awọn to ni ijamba ọkọ lagbegbe Ajebọ, ni J4, loju ọna marosẹ Sagamu si Ijẹbu-Ode, nipinlẹ Ogun, ni wọn ti…

Ẹ woju awọn to wa nidii akọlu ti wọn ṣe si ọfiisi ijọba ipinlẹ Ọyọ

Ọlawale Ajao, Ibadan Ọkan awọn ara ipinlẹ Ọyọ ti balẹ bayii pẹlu bi ọwọ awọn agbofinro…

Eyi niṣẹ ti Ẹniọla Ajao ran si Bobrisky lọgba ẹwọn

 Monisọla Saka Oṣerebinrin ilẹ wa nni, Ẹniọla Ajao, to ni sinnimọ ‘Ajakaju’, ti Idris Ọlarewaju Okunẹyẹ,…