Ogunṣua Mọdakẹkẹ ti waja! 

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ogunṣua ilu Mọdakẹkẹ, Ọba Moses Ọladẹjọ Oyediran, Ajombadi Kẹta, ti darapọ mọ awọn…

 Awa la sin Timothy Adegoke, inu paali la ti ba oku rẹ – Wolewole

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ni itẹsiwaju igbẹjọ iku akẹkọọ Fasiti Ifẹ to ku si otẹẹli Hilton, loṣu…

Ẹgbẹ oṣelu APC bura fawọn oloye tuntun ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọruu, Wẹsidee, ọṣẹ yii, ni ẹgbẹ oṣelu APC, ẹka tipinlẹ Kwara, bura fun…

Ọjọgbọn Adebayọ Bamirẹ di ọga agba tuntun fun Fasiti Ifẹ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Awọn alakooso ileewe Ọbafẹmi Awolọwọ, Ileefẹ, ti kede Ọjọgbọn Simeon Adebayọ Bamirẹ gẹgẹ…

Ọpọlọpọ owo, aṣọ ileewe awọn akẹkọọ ati iwe ni wọn ba lọwọ obinrin to n ṣe bii were yii ni n’llọrin

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin L’Ọjọbọ, Tọsidee, ọṣẹ yii, lọwọ tẹ obinrin afiniṣowo kan to n dibọn bii…

Iwadii fihan pe ko si aisan kankan lara Adegoke titi to fi ku – Dokita 

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Dokita akọṣẹmọṣẹ nipa ayẹwo si ara oku (Consultant Pathologist), to n ṣiṣẹ pẹlu…

PDP yoo ṣeto idibo abẹle funpo aarẹ ninu oṣu karun-un

Adewumi Adegoke Ti gbogbo nnkan ba lọ bi wọn ti ṣeto rẹ, opin oṣu Karun-un, ọdun…

APC fagi le ipade ọmọ igbimọ ẹgbẹ to yẹ ko waye ni Tọsidee

 Jọkẹ Amọri Ẹgbẹ oṣelu APC ti fagi le ipade awọn ọmọ igbimọ ẹgbẹ naa to yẹ…

‘Biṣọọbu’ fipa ba ọmọ rẹ ati t’aladuugbo wọn lo pọ n’Ipaja, lo ba ni wọn purọ m’oun ni

 Jọkẹ Amọri Niwaju ile-ẹjọ to n ri si ẹsun lilo ọmọ nilokulo ati fifipa ba ọmọde…

Buhari ti sọrọ, o ni Buni ni ko ṣeto idibo gbogbogboo APC

Faith Adebọla Bo tilẹ jẹ pe Aarẹ Muhammadu ko si nile, to jẹ ilu oyinbo lo…

Nitori ọrọ ti ko to nnkan, Soobata gun ọmọ lanlọọdu ẹ pa l’Ondo

Iyiade Oluṣẹyẹ, Akurẹ Titi di ba a ṣe n sọ yii lawọn eeyan ṣi n sọ…