Ti mo ba di aarẹ, ma a tu Sunday Igboho ati Kanu silẹ kiakia – Ṣoworẹ  

Faith Adebọla Gbajugbaja ajijagbara ati oniroyin ori atẹ ayelujara nni, Ọmọyẹle Ṣoworẹ, ti kede pe ti…

Oni nigbẹjọ Adedoyin atawọn oṣiṣẹ rẹ yoo bẹrẹ niluu Oṣogbo

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Oludasilẹ ileetura Hilton, niluu Ileefẹ, Dokita Rahmon Adedoyin, ati mẹfa lara awọn oṣiṣẹ…

Ọgọfa ọmọ Naijiria fẹẹ lọ jagun ni Ukraine, wọn lawọn maa gbeja wọn

Faith Adebọla Pẹlu bijọba Naijiria ṣe n sapa lati ko awọn ọmọ Naijiria ti ogun to…

Ọkunrin yii gbe awọn ibẹta niyawo lọjọ kan naa, o ni wọn ti jọra wọn ju  

Keeyan gbeyawo kan, tabi ko fẹ obinrin meji ọtọọtọ papọ ti waye ri, ṣugbọn boya ni…

Wọn ti mu Ahmed to pa alaabagbe rẹ nitori abọ ounjẹ n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Wọn ni ẹgbẹrun saamu kan ko le sa mọ Ọlọrun lọwọ, lọjọ Iṣẹgun,…

Ọbasanjọ ṣabẹwo si Olubadan ti wọn ṣẹṣẹ yan

Ọlawale Ajao, Ibadan Lọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọsẹ yii, ni aarẹ ilẹ wa tẹlẹ, Oloye Oluṣẹgun Ọbasanjọ,…

Ẹ tọju kaadi idibo yin, ki ẹ le fi le ẹgbẹ APC, PDP sọnu l’Ekiti-Oni

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Gomina ipinle Ekiti tẹlẹ, Oloye Ṣẹgun Oni, ti rọ awọn eeyan ipinlẹ Ekiti…

Nitori ija oun ati Tinubu: Alaafin, Ọọni ṣepade pẹlu Arẹgbẹṣọla

Lọjọ kin-in-ni, oṣu Kẹta yii, ni ALAROYE gbọ latẹnu awọn to mọ bo ṣe n lọ…

APC fa Monisade Afuyẹ kalẹ lati dupo igbakeji gomina l’Ekiti

Taofeek Surdiq, Ekiti Wọn ti fi orukọ Abilekọ Monisade Christiana Afuyẹ to jẹ Olori awọn obinrin…

Ijọba apapọ rọ kootu lati fagi le idajọ ile-ẹjọ to ni ki wọn fun Sunday Igboho lowo nla

Ọlawale Ajao, Ibadan Nitori bi ile-ẹjọ ṣe paṣe pe ki wọn san biliọnu lọna ogun Naira…

Oju oorun ni Dauda ti dide, o si ja bọ latori ile alaja mẹta n’Ilọrin, lo ba ku patapata 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Oorun ni gende-kunrin ẹni ọgbọn ọdun kan, Ọgbẹni Dauda, lọọ sun lori ile…