Kẹhinde dana sun ale ọkọ ẹ l’Ọta

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Obinrin ọlọmọ mẹta kan ti wọn pe orukọ ẹ ni Kẹhinde Abdul Wasiu, ti…

Awọn araalu n beere fun idajọ ododo lori Kabir ti ọlọpaa kan yinbọn pa l’Oṣogbo

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Bi ọrọ ọlọpaa naa jẹ ẹfun tabi eedi, awọn eeyan agbegbe Ọta-Ẹfun, niluu…

Nitori iku akẹkọọ kan, ijọba ti ileewe Dowen College pa

Faith Adebọla, Eko Latari iku ojiji to pa ọkan lara awọn akẹkọọ wọn, Sylvester Oromoni, ọmọọdun…

Nitori bawọn kan ṣe pa akẹkọọ ẹlẹgbẹ wọn nibẹ,  ijọba  ti ileewe Dowen College pa

Faith Adebọla, Eko Latari iku ojiji to pa ọkan lara awọn akẹkọọ wọn, Sylvester Oromoni, ọmọọdun…

Ẹwọn n run nimu Ṣeyi o, aṣẹwo lo fipa ba lo pọ n’Ilupeju-Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ile-ẹjọ Majisreeti kan to wa ni Ado-Ekiti ti paṣẹ pe ki wọn fi…

Ọsẹ to n bọ ladajọ yoo ṣepinnu lori akọsilẹ ti Baba Ijẹṣa ṣe lagọọ ọlọpaa

Faith Adebọla, Eko Adajọ Oluwatoyin Taiwo tile-ẹjọ akanṣe to wa n’Ikẹja ti sọ pe ọjọ kẹẹẹdogun,…

Awọn Fulani ji tọkọ-tiyawo gbe l’Ẹsa-Oke, miliọnu mẹtadinlogoji naira ni wọn n beere bayii

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Tọkọti-yawo kan, London ati Blessing Omoru, ti wọn n gbe ni abule awọn…

Awọn eleyii lo maa n ba awọn ajinigbe ra ounjẹ, ko ọta ibọn ati ibọn tuntun wọle

Faith Adebọla  Ileeṣẹ ọlọpaa apapọ ilẹ wa ti ṣafihan awọn afurasi ọdaran mejilelọgbọn kan niluu Abuja…

Ẹ fura o: Korona tuntun, Omicron, ti de Naijiria

Faith Adebọla Ajọ to n gbogun ti itankalẹ arun lorileede yii (Nigeria Centre for Disease Control)…

Ijọba ti geeti mọ awọn oṣiṣẹ ti ko gba abẹrẹ Korona

Faith Adebọla Niṣe nijọba ti geeti to wọle si awọn ileeṣẹ ọba gbogbo lọjọ Aje, Mọnde,…

Ọṣun 2022: Ẹni to ba dupo gomina pẹlu Oyetọla fẹẹ fi owo rẹ ṣofo ni – APC

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Awọn ọmọ ẹgbẹ oṣelu APC ni iha ẹkun idibo Ẹdẹ, iyẹn Ede Federal…