Faith Adebọla Latari awuyewuye to gbode kan nigba tawọn eeyan ri minisita feto irinna…
Sanwo-Olu wo awon ile kan ni Banana Island, o ni wọn lufin ijọba
Nitori ti wọn kọle si ibi ti omi le maa gba kọja lawọn eeyan kan ṣe…
Sanwo-Olu kilọ fawọn ọdọ to fẹẹ ṣewọde ta ko ṣiṣi Too-geeti Lẹkki pada
Faith Adebọla Gomina ipinlẹ Eko, Babajide Oluṣọla Sanwo-Olu, ti sin awọn ọdọ to n gbero lati…
Eeyan mẹfa ku, ọwọ tẹ mọkadinlogun, nibi ija awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun ni Dalemọ ati Alakukọ
Kazeem Aderounmu O kere tan, ọmọ ẹgbẹ okunkun mọkandinlogun lọwọ awọn agbofinro tẹ lagbegbe Alakukọ, niluu…
Ijọba lu awọn mọto to lufin irinna ni gbanjo l’Ekoo
Jide Alabi Mọto oriṣiiriṣii bii mẹtalelọgọrin (83) ni ijọba Eko lu ni gbanjo lọjọ Aje, Mọnde,…
Awọn janduku kọ lu oloye ẹgbẹ APC meji nibi ipade kan ni Lafiagi
Stephen Ajagbe, Ilorin Ọrọ di bo o lọ o yago lọna lọjọ Aje, Mọnde, ọsẹ yii,…
Nitori Aunty Ramota, ija nla bẹ silẹ laarin Iya Ereko ati oṣere mi-in, ọpẹlọpẹ Mr Latin
Kazeem Aderounmu Fidio kan lo kọkọ wa lori ikanni ẹrọ ayelujara, Instagiraamu ti Jamiu Azeez, ọkan…
Olukọ ileewe giga fi foto obinrin lu oyinbo ni jibiti niluu Ọffa
Stephen Ajagbe, Ilorin Olukọ ileewe giga College of Health Technology, niluu Ọffa, nipinlẹ Kwara, Ọpaṣhọla Abdullahi,…
Awa ara Ibarapa ni: A fẹ kijọba waa ba wa le Wakili, nitori ko fi awa araalu lọkan balẹ
Ọlawale Ajao, Ibadan Bo tilẹ jẹ pe ojoojumọ lawọn ara Ayetẹ, nijọba ibilẹ Ariwa Ibarapa, nipinlẹ…
Nitori bi awọn tọọgi ṣe lu wọn lalubami, awọn nọọsi fẹhonu han l’Ọwọ
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ẹgbẹ awọn nọọsi ileewosan ijọba apapọ to wa niluu Ọwọ, ni…
Ẹni ba da wahala silẹ nibi eto iforukọsilẹ APC yoo da ara rẹ lẹbi – Samari
Stephen Ajagbe, Ilorin Kaakiri ijọba ibilẹ mẹrindinlogun to wa nipinlẹ Kwara ati ibudo idibo…